Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ

This is a Nigeria news category

Ènìyàn méjì- lé- lọ́tà- lélọ́ọ̀dúnrún míràn tún ti ní ààrùn covid

Ní ọjọ́ àìkú,ọjọ́ kọkàn – dín – lọ́gbọ̀n oṣù kẹjọ,ọdún 2021, àwọn ènìyàn méjì- lé –lọ́tà –lélọ́ọ̀dúnrún míràn tún ti ní ààrùn covid, gẹ́gẹ́ bí ilé – iṣẹ́ tó ń mójútó àjàkálẹ̀ ààrùn ṣe kéde rẹ̀ ní…

Ìdíje ẹrẹ́ bọ́ọ̀lù ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ àgbáyé: Rohr pe ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Super Eagles ọgbọ̀n (30)

Bi idije ere bọọlu ifẹsẹwọnsẹ ti agbaye yii se n sunmọ itosi,, akọnimọọngba  fun ikọ agbaabọọlu Super Eagles, Gernot Rohr ti pe awọn agbabọọlu ọgbọn (30)  ti yoo maa kopa ninu idije ere bọọlu agbaye (FIFA World Cup qualifying) ti yoo maa…

Ẹgbẹ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Nàíjíríà (NANS) sèlérí láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àjọ EFCC láti…

Àgbárijọ ẹgbẹ́ àwọn  akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà (NANS) ti seleri láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹlu àjọ tó ń gbógun ti ìwà ìbàjẹ́ àti síse owó ìlú kúmọkùmọ, EFCC  láti dojú ìjà kọ ìwà jàǹdùkú orí ẹ̀rọ…

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ kó àwọn akẹ́kọ̀ọ́ márùndínláàdọ́rùn ún ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́…

Ìjọba  ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lábẹ́ àkóso gomina Seyi Makinde ti kó àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí í se ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tí ó tó márùndínláàdọ́rùn ún kúrò ni ìpínlẹ̀ Plateau látàri ́rògbòdìyàn tó ń sẹlẹ̀ níbẹ̀. Ninu…

Ìkọ́lú àwọn ọmọ ilé-ẹ̀kọ́ gíga ààbò NDA Yóò pèwón níjà – Ààrẹ Buhari

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí sọ pé,àjálù tí ó kọlu ilé -ẹ̀kọ́ gíga Ìdáábòbò Nàìjíríà (NDA) ní ọjọ́ ìṣẹ́gun,kò yẹ kí wọn jẹ́ kí ó dẹ́rùbà ìgboyà wọn, bí kò ṣe  pé, kí wọn ri bíi ìpeni níjà láti fi  …