Browsing Category
ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ
This is a Nigeria news category
Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ní Ìlà Oòrùn Gúsù Ti Kìlọ Látàrí Ìpè Ìpàdé Àwọn Alẹ́nulọ́rọ̀ Tó Jẹ́ Òfegè
Ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP Ní Ìlà Oòrùn Gúsù ti kìlọ fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀ láti má ka ìpè ipàdé pàjáwìrì àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ ní Abuja sí.
Nínú àkọsílẹ̀ ìròyìn kan, alukoro ẹgbẹ́ ní ẹ̀ka ìlà oòrùn gusu, Chigozie Igwe, tẹnumọ…
Burna Boy Yóò Se Eré Ọ̀fẹ́ Fún Àwọn Ololufẹ Rẹ̀ Ní Orílè-èdè Burkina Faso
Ìràwọ akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sọ èyí di mímọ̀ lórí ẹ̀rọ ayélujára Instagramu rẹ̀ ni ọjọ́ kẹtàdínlogun oṣù kàrún ọdún 2025 pé òun ṣe eré ní orílẹ̀-èdè Burkina Faso.
"Ti o bá seése, fún mi, iyì ni yóò jẹ fún mi láti seré ọ̀fẹ́…
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kéde Ìbẹ̀rẹ̀ Àjọ̀dún Eré Ìdárayá Orílẹ̀-èdè
Tí ìdùnnú tí ayọ̀ ní gbogbo àwọn ènìyàn wà nílùú Abeokuta, tó jẹ́ olu-ilu ìpínlẹ̀ Ogun, nígbà tí Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣe kéde ayẹyẹ eré ìdárayá ẹlẹ́ẹ̀kejìlélógún ní ìforígbárí, pẹ̀lú àwọn olóyè, àwọn olóṣèlú, àwọn ògbóǹtagí eré ìdárayá…
Nàìjíríà Yóò Gbàlejò Àwọn Ilé iṣẹ́ Ọkọ̀ Oníná Tí China
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣètò láti gbàlejò àwọn ilé-iṣẹ́ ọkọ̀ ayọkẹlẹ oníná bí Orílẹ̀-èdè China tí n kéde ìpinnu wọ́n.
Aṣojú Ilú China sí Nàìjíríà, Yu Dunhai, sọ èyí l'àkókò àbẹwò kán sí Mínísítà fún Àwọn òun alumọni tó lágbára tí…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Gombe Bá Àwọn Àrinrìn-àjò Hajj Ẹgbẹ̀rún dín-ní-ogójì-dín-méjì Yọ̀
Gómìnà Muhammadu Yahaya tí Ìpínlẹ̀ Gombe tí fí ọrọ ránṣẹ́ sí àwọn àrinrìn-àjò ẹgbẹ̀rún-dín-ní-ogójì-dín-méjì (962) tí wọ́n fẹ́ ẹ ṣé Ìrìn-àjò sí Makkah fún Hajj l'ọdún 2025, Saudi Arabia.
Nígbàtí o n sọrọ níbí ayẹyẹ idagbere náà ní…
FRSC J’àbọ̀ Adínkù Ìjàmbá Ọkọ Ṣùgbọ́n Ìjàmbá Olóró Ń Pọ Sí
Àwọn Ẹ̀ṣọ Ojú Pópó Tí Ìjọba Àpapọ̀ (Federal Road Safety Corps FRSC) tí j'àbọ̀ ìròyìn adínkù ìdá mẹ́wàá 10% lápapọ̀ àwọn ìjàmbá òpópó-ọ̀nà láàrin ọdún 2023 àti 2024, sùgbọ́n ìdá méje 7% ní àwọn tó f'ara gbá ìjàmbá náà tó kú.
Corps…
Àtúntò Ètò-Ẹ̀kọ́ Ààrẹ Tinubu Fún Ọjọ́-Iwájú Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́
Bí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gbé ìgbésẹ akin lórí àtúntò Orílẹ̀-èdè, ìṣàkóso Ààrẹ Bola Tinubu gbé ètò-ẹ̀kọ́ àti ìdàgbàsókè ọgbọ́n sí ọkàn nínú èro ìyípadà àti àtúntò rẹ̀.
Ètò ìmúlò Ètò-Ẹ̀kọ́ lábẹ́ Ètò Ìrètí Túntún ṣé pàtàkì ànfàní, ètò…
Ààrẹ Nàìjíríà Ṣàtúnṣe Ìgbìmọ̀ Eré Ìdárayá Orílẹ̀-èdè Fún Ìlọsíwájú
Ààrẹ Bola Tinubu kéde àtúnṣe tí Ìgbìmọ̀ Eré Ìdárayá tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (National Sports Commission NSC) tó tí wá fún ìgbà pípẹ́ láti dáàbòbo ìṣàkóso eré ìdárayá kúrò lọ́wọ́ àwọn ìdádúró ìjọba àti àwọn ìdíwọ́ mìíràn.
Ààrẹ ló sọ…
Ọ̀sẹ̀ Àṣà Ìlú Ìbàdàn Tí 2025: Makinde Ṣèlérí Láti Fún Àwọn Olórí Ìlú Ní Ẹ̀tọ́ Wọn.
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ṣèlérí pé ìṣèjọba òun kò ní fi ẹ̀tọ́ àwọn olórí ìlú dùn wọ́n.
Gómìnà ló sọ ọ̀rọ̀ yii di mímọ̀ níbi àṣèkágbá ayẹyẹ ọsẹ̀ àṣà ìlú Ìbàdàn to wáyé ni pápá ìṣeré Obafemi Awolowo, ni agbègbè Òkè-Ado, ni ìlú…
Hajj 2025: Kwara gbé àwọn arìnrìn àjò mímọ́ ikọ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹta ti ẹdẹ̀ẹ́gbẹ̀ta-ó-lé-ọgọ́ta Lọ…
Ikọ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹta àwọn arìnrìn àjò mímọ́ tí ó tó ẹdẹ̀ẹ́gbẹ̀ta -ó -lé -ọgọ́ta láti ìpínlẹ̀ Kwara gbéra lọ sí Saudu Arabia ní ọjọ́ Àbámẹ́ta láti ṣe iṣẹ́ mímọ́, tí ó sì jẹ́ pé ọkọ̀ òfurufú Max ni ó gbé wọn láti…