Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN

This is a category for featured story

Àwọn Ọmọ-ogun Ṣàfihàn Ẹní Tó Ń Ṣètò Ìpara-ẹni Láàrin Ìlú Ní Àríwá-Ìlà Oòrùn

Àwọn Ọmọ-ogun tó ń ṣiṣẹ́ ní Àríwá-Ìlà Oòrùn Nàìjíríà HADIN KAI (OPHK) tí fí Ọ́gbẹ́ni Shariff Umar hàn gẹ́gẹ́ bí ẹní tó ń ṣètò ìpara-ẹni láàrín ìlú pẹ̀lú ado olóró tó ṣẹ̀ṣẹ̀ wáyé, èyí tí àwọn Ológun náà tí gbìyànjú láti dúró. ‎ ‎Èyí ni…

Ààrẹ Tinubu Pàṣẹ Pé Kí Wọ́n Bẹ̀rẹ̀ Sí Máa Wá Àwọn Tó Ṣékọlù Kasuwan Daji ‎

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí pàṣẹ fún Mínísítà fún ààbò, Olórí Àwọn Ológun, Àwọn Olórí Gbogbo Àwọn Ọmọ Ológun, Olórí Àwọn Ọlọ́pàá, àti Olùdarí Àgbà ti Ẹ̀ka Àwọn Iṣẹ́ Ìpínlẹ̀ (DSS) láti wá àwọn tó ṣe ìkọlù sí Kasuwan Daji kí wọ́n sì mú wọn ní…

Àwọn ọmọ ológun ti gba àwon ará ìlú tí wón jí gbé ní ìpínlẹ̀ Borno sílẹ̀

Àwọn ọmọ-ogun ti Operation HADIN KAI (OPHK) tún ti ṣe àṣeyọrí pàtàkì mììràn lẹ́nu iṣẹ́ wọn, nígbà tí wọ́n farabalẹ̀ kán lu àwọn oníjàgídíjàgan kan ní ìjọba ìbílẹ̀ Konduga, ti Ìpínlẹ̀ Borno, léèyí tí ó yọrí…

Ilé-Iṣẹ́ Ọkọ̀ Ojú Irin Nàìjíríà Bẹ̀rẹ̀ Déédé Owó Ojú-Irin  ‎

 ‎Ilé-Iṣẹ́ Ọkọ̀ Ojú-Irin Nàìjíríà (NRC) ti fi dá àwọn arìnrìn-àjò lójú pé wọ́n ń gbìyànjú láti mú kí iṣẹ́ ọkọ̀ ojú irin dára síi, ìtùnú, àti ààbò lórí gbogbo iṣẹ́ ọkọ̀ ojú irin bí wọn ṣe bẹ̀rẹ̀ déédéé owó ọkọ ojú irin náà ní ọjọ́ Àìkú, ọjọ́…
button