Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN

This is a category for featured story

Ààrẹ Nàìjíríà Tí Fọwọ́sí Gbígba Àwọn Ẹ̀ṣọ́ Igbó ‎

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí fọwọ́sí ìgbanísíṣẹ́ tí àwọn ẹ̀ṣọ́ igbó gẹ́gẹ́bí isọdọtun àwọn ìlànà orílẹ̀-èdè láti ní Ààbò àti gbá àwọn igbó Nàìjíríà pàdà lọwọ́ àwọn ọ̀daràn àti àwọn arufín ilú. ‎ ‎ Ìpinnu náà ní èròngbà látí tẹra mọ iṣẹ́…

Nàìjíríà Ṣé ìfihàn Ìgbésẹ̀ Àtúnṣe Òfin Tí Ọọ̀ràn-Orí-Ayélujára

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí n ṣé àfihàn ìgbésẹ̀ àtúnṣe tí Òfin Ọọ̀ràn-Orí-Ayélujára, gẹ́gẹ́bí Mínísítà fún ìròyìn àti Àlàyé tí Orílẹ̀-èdè, Mohammed Idris, ṣé ìdánilójú imurasilẹ ìjọba láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin tí Orílẹ̀-èdè, àwọn…

Ìpínlẹ̀ Kaduna: Àwọn Ènìyàn Ìpínlẹ̀ Náà Parapò Láti Ṣe Àjoyọ́ Ọjọ́ Àlàáfíà.

Àwọn ará agbègbè ìpínlẹ̀ Kaduna ti pejo láti ṣe àfihàn ifẹ, irepo àti ìsọkan láàrin ara wọn ní ojọ́ kerindinlogun oṣù kàrún ọdún, 2025. Ààrẹ ẹgbẹ́ àlàáfíà ti onigbagbọ wọn pẹ ni PRRFON  alàgbà Buru kí àwọn ènìyàn tó jẹ Musulumi káàbò sí…

Ààrẹ Tinubu Gbé Òsùbà O káre Fún Oníròyìn Àgbà Bisi Olatilo Fún Àádọta Ọdún Lẹnu Iṣé Ìròyìn.

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bola Ahmed Tinubu ti gbé Òsùbà o káre fún Aláṣẹ àti Olùdarí ilé iṣé Biscom Communication, Ọmọba Bisi Olatilo fún ayẹyẹ àádọta ọdún lénu iṣé ìròyìn. Ààrẹ gbóríyìn fún ọmọba Olatilo fún akitiyan, ipá mọra, ìfẹ àti…

Ètò Ìlera Ọ̀fẹ́: Makinde Ṣíde Ìfilọ́lẹ̀ Ìlera Ọ̀fẹ́ Ní Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá/Ìlà-Oòrùn Ìbàdàn.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti jẹ ko di mímọ̀ pé ìṣèjọba òun yóò tẹ síwájú láti máa pèsè ètò ìlera lójúnà àti ri dájú pé ará ìlú wa ni ìlera pípé eléyìí tí yóò mú kí ọrọ̀ ajé rú gọ́gọ́ síi, ti ìṣẹ yóò sì dínkù ni àwùjọ. Makibde…
button