Browsing Category
KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN
This is a category for featured story
Gómìnà Zulum Gbàlejò Ìpàdé Àsà Ti Kanem-Borno
Gomina ipínlẹ̀ Borno, Babagana Umara Zulum, ti gbàlejò ìpàdé ọ̀gọ̀rọ̀ ẹgbẹgbẹ̀run ẹ̀yà ènìyàn Kanuri ó kéré tán orílẹ-èdè mẹ́wàá láti Ilẹ̀ Adúláwọ̀ tó wá síbi ìpàde àṣà ti Kanem-Borno tó wáyé ní ìlú Maiduguri.
Ìpàdé náà ṣe àgbájọpọ̀…
Wọ́n Kọ̀ Láti Gbá’dúró Alátakò Ìjọba Ùgándà Kizza Besigye
Lẹ́yìn ọdún kan tí wọ́n ti mú un, ilé ẹjọ́ gíga orílẹ̀-èdè náà ti kọ̀ láti gbá òní'dúró alátakò Ìjọba Ùgándà Kizza Besigye kúrò nínú túbú.
Wọ́n ti fi ẹ̀sùn ìṣọ̀tẹ̀ kan Besigye nítorí pé ó gbèrò láti fi agbára mú ààrẹ Yoweri…
Lookman, Chelle Wà Lára Agbábọ́ọ̀lù Mọkànlá Tó Yarantí Jùlọ Tí Wọ́n Dárúkọ Ní Ìdíje AFCON Ọdún 2025…
Agbábọ́ọ̀lù ará ipò iwájú Super Eagles orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Lookman àti akọ́nimọ̀ọ́gbá, Eric Chelle ní wọ́n ti kéde pé wọ́n wà lára agbábọ́ọ̀lù mọkànlá tó yarantí jùlọ ní ìpele àkọkọ tí Idije Africa Cup of Nations (AFCON), Ọdun…
Ìtọ́nisọ́nà Ṣé Pàtàkì Sí Ìgboyà Láti Darí Gẹ́gẹ́bí Aṣáájú Dáadáa – Mínísítà
Mínísítà fún Ìròyìn àti Ìtọ́sọ́nà Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mohammed Idris, ti tẹnu mọ́ ìmọ̀ràn àti ìtọ́sọ́nà gẹ́gẹ́ bí òun pàtàkì sí ìgboyà fún ẹnikẹ́ni láti darí bí aṣáájú réré.
Mínísítà fún Ìròyìn sọ ọ̀rọ̀ yìí níbi ìpàdé kan tí…
Gómìnà Nwifuru Gbóríyìn Fún Àwọn Àṣeyọrí Ni Orísirísi Ọnà Ni Ìpínlẹ̀ Ebony.
Gómìnà Francis Nwifuru ti gbóríyìn fún àwọn àṣeyọrí àti àwọn ìdàgbàsókè to sẹlẹ̀ ni ìpínlẹ̀ Ebony nipa ètò Ẹ̀kọ́ àti ìlera.
Nwifuru so èyí di mímọ̀ lásìkò to n ṣe idupẹ nile ìjósìn láti sààmì sí ayẹyẹ ọdun ìjọba awaarawa ni Abakaliki.…
Ìpínlè Anambra: Ṣẹ́nítọ̀ Bí Ẹnu Àtẹ Lu Bí Wọn Ṣe Ti Ọjà Onitsha Pa Fún Ìgbà Pípẹ́.
Dọ́kítà Tony Nwoye to jẹ Ṣẹ́nítọ̀ to n sojú ìpínlẹ̀ Anambra ti bu ẹnu àtẹ lù bí wọn ṣe tí ọjà Ogbo Ogwu ti wa ni onitsha pa fún ìgbà pípẹ́ báyìí
Ó ni àwọn ilé ìtajà to to egbegberun márùn-un ni àjọ tó n mójú tó ọrọ oúnjẹ àti ògùn NAFDAC…
Olóyè Pàtàkì Ni Ile Ẹjọ Gíga Jùlọ Rọ Awon Adájọ Láti Se Ìdájọ Pèlú Àánú.
Olóyè Pàtàkì ni ilé ẹjọ́ gíga jùlo ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Kabir Akanbi ti rọ àwọn adájọ kàkàkí Orílè-èdè Nàìjíríà láti ṣe ìdájọ pèlú Àánú lójú.
Nígbà tí o ṣe Ẹgbẹ́ àwọn adájọ ti ìlú Abuja ( NAJUC) se ìbẹ̀wọ̀ sí Akanbi ni o ti rọ wọn…
Àwọn Òṣìṣẹ́ Elétò Aláàbò Dènà Àdó Olóró Láti Du Gbámú Ni Ìpínlẹ̀ Anambra.
Àwọn elétò òṣìṣẹ́ aláàbò nì ìpínlẹ̀ Anambra ti ba ìmọ̀ àwọn ènìyàn oníṣe laabi jẹ latari bi wọn ṣe dènà àdó olóró láti bí gbámú ni ìpínlẹ̀ náà
Lásìkò tí wọn ṣe àyẹwò sí ìbi ifarapamo àwọn ènìyàn oníṣe laabi náà tó wà ni ìjọba ìbílẹ̀…
Igbákejì ÀàrẹTanzania pè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láti gbógun ti eebi
Igbákejì ÀàrẹTanzania, Philip Mpango ti pé fún ìṣọ̀kan àgbáyé láti kojú ebi àti ìpọ́njú, wípé orílẹ̀ èdè kan kò le dá ogun náà jà.
Gẹgẹ bi alaye kan ti o jade lati ile iṣẹ igbakeji Aarẹ ni ọjọ Ẹti, Mpango pe ipe…
Gómìnà Plateau kí àwọn aṣojú PDP káàbọ̀ fún àpèjọ Àríwá Àringbùngbùn
Gómìnà ìpínlẹ̀ Plateau, Caleb Mutfwang, ti gba àwọn aṣojú ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP) láti Àríwá Àringbùngbùn lálejò fún oúnjẹ alẹ́ kí ìpàdé agbègbè ẹgbẹ́ láti yan àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tuntun tó…