Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN YÀJÓ-YÀJÓ

This is a category for TRENDING NOW

Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Naijiria bèèrè fún Ìṣojú nínú ìgbìmọ̀ NELFUND

Ẹgbẹ́ àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ Naijiria lapapọ, NANS, ti bèèrè fún Ìṣojú nínú apejọ ìgbìmọ̀ tí ń rí sí Owó yíyá fún Ẹ̀kọ́ ní Nàìjíríà, NELFUND, pé bí àwọn ṣe jẹ́ olùjàǹfààní àkọ́kọ́ fún owó yíyá náà, wọ́n…

Mínísítà kí Ìyáàfin Tinubu kú oríire fún yíyàn án ní ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ Alákòóso…

Mínísítà fún Ọ̀rọ̀ àwọn Obìnrin, Imaan Sulaiman-Ibrahim, ti kí Arábìnrin kìíní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Sẹnetọ Oluremi Tinubu, lóríi bí wọ́n ṣe yàn án  ní ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ Alákòóso àwọn Arábìnrin Àkọ́kọ́…

Arábìnrin Kìínní Nàìjíríà di ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ alákòóso OAFLAD

Wọ́n ti yan Arábìnrin Kìínní Nàìjíríà, Oluremi Tinubu gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ igbìmọ̀ Alákòóso fún Àjọ àwọn Arábìnrin kìíni fún Ìdàgbàsókè (OAFLAD), ipele Ìṣàkóso tó ga jùlọ nínú ẹgbẹ́ náà. Eleyi waye…

Ààrẹ Tinubu ṣàjọyọ̀ pẹ̀lú ògbóhùntarìjgì òṣèré Nkem Owoh ní ààdọ́rin ọdún

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti kí ògbóhùntarìjgì òṣèré Nollywood, apanilẹ́ẹ́rín,akọrin tí ó tún jẹ́ olukọ̀ọ orin, Ọ̀gbẹ́ni Nkem Owoh, MON, bí ó ṣe ń ṣe ọjọ́ ìbí ààdọ́rin ọdún rẹ̀. Lori ajọyọ naa, aarẹ Tinubu gboriyin…

Ilé iṣẹ́ ìjọba tí ń rísí ọ̀rọ̀ àwọn obìnrin yóò ṣàgbékalẹ̀ ìlànà ilé ìfowópamọ́…

Ilé iṣẹ́ ìjọba tí ń rísí ọ̀rọ̀ àwọn obìnrin ní Nàìjíríà yóò ṣàgbékalẹ̀ ìlànà ilé ìfowópamọ́ alábọ́ọ́dé lórílẹ̀-èdè fún àwọn olùṣòwò jákèjádò Nàìjíríà. Minisita fun ọrọ awọn obinrin, Imaan…

Ìjọba Nàìjíríà túnbọ̀ fìdí ìpinnu rẹ̀ lórí ìrìnàjò lọ sílùú mìíràn lọ́nà…

Ìjọba Nàìjíríà ti túnbọ̀ fìdí ìpinnu rẹ̀ láti ri pé àwọn ìrìnàjò láti Nàìjíríà lọ sí àwọn orílẹ̀-èdè  mìíràn wáyé lọ́nà tó bòfin mu múlẹ̀, tí ó sì ṣàlàyé àǹfààní ọrọ̀ ajé àti ìdábòbò…
button