Browsing Category
ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GBÌN
Ìjọba Nàìjíríà Se Àgbékalẹ̀ Ìgbìmọ̀ Tí Yóò Sàgbéyẹ̀wò Ìpalára Ìyípadà Ojú Ọjọ́
Ìjọba Àpapọ̀ ti ṣe àgbékalẹ̀ ìgbìmọ̀ láti se àmúsẹ àfẹnukò lórí ìpalára tí ìyípadà ojú ọjọ́ ń fà ní àwùjọ wa. Èyí tí ó wáyé ní ìlú Nguru, ìpínlẹ̀ Yobe, orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
…
Ìpínlẹ̀ Edo Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Àgbẹ̀ Ọlọ́sìn Adìẹ
Ìjọba ìpínlẹ̀ Edo, pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn ilé iṣẹ́ ọlọ́sìn Adìẹ yóò se ìrànlọ́wọ́ fún àwọn àgbẹ̀ ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500,000).
Ó fi ọ̀rọ̀ náà léde níbi àpéjọ kan ní Ikpoba, ìjọba…
Ìjọba Pín Ohun Èlò Ọ̀gbìn Fún Àwọn Tí Ó Lùgbàdì Omíyalé
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ondo ti bẹ̀rẹ̀ láti máa pín ohun èlò ọ̀gbìn fún àwọn tí omíyalé dà láàmú lójúnà àti ṣe ìgúnpá fún wọn àti fún ìtẹ̀síwájú ètò ọ̀gbìn.
Gómìnà ìpínlẹ̀ náà, Rotimi Akeredolu…
Emir Gbóríyìn Fún Ìjọba Ìpínlẹ̀ Gombe Lórí Ọ̀gbìn Alikama
Emir ìlú Nafada, ìpínlẹ̀ Gombe, Alhaji Muhammadu Hamza ti lu ìjọba ìpínlẹ̀ náà lọ́gọ ẹnu fún síse ìgúnpá fún àwọn àgbẹ̀ tí ó ń gbin alikama (wheat) ní ìpínlẹ̀ náà.
Ó fi ọ̀rọ̀ náà léde ní ààfin…
Gbajúgbajà Ọdẹbìnrin Rí Àgbéga Lórí Ètò Ààbò
Akin obìnrin tí ó jẹ́ ọdẹ, Aisha Bakari ti rí ìyànsípò gẹ́gẹ́ bíi adarí àwọn ọdẹ tí ó gbógun ti ìgbésùmọ̀mí àti ìgbénipa, (Directorate of Hunting and Forestry of the Nigerian Hunter and Forest Security Services, NHFSS).…
Oúnjẹ yóò wà lọ́pọ̀ janturu ní 2023 – ilé-iṣẹ́
Ilé-iṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tó ń rísí ètò Ìdàgbàsókè ilẹ̀ ọ̀gbìn (NALDA),ti ṣàlàyé pé, kò ní sí àìtó oúnjẹ ní orílẹ̀-èdè, tí ó sì tún ń fi dá àwọn ọmọ Nàìjíríà lójú pé eebi kò ní pa wọ́n ní ọdún…
Ìpínlẹ̀ Edo Ṣé Ìfilọ́lẹ̀ Ọ̀gbin Ìgbà Ẹẹ̀rún 2022 Wọn Pín Ohun-Èlò Ìbomirin
Ìjọba Ipinlẹ Edo tí ṣé ifilọlẹ ogbin Ẹẹ̀rún 2022, wọ́n sì tún pín Ohùn-Èlò Ibòmírín fún àwọn Agbẹ tí wọ́n le ni Ẹẹdẹgbẹ̀tá láti jẹ kí oúnjẹ pọ yanturu kárí ọdún.
FADAMA EDO ni ó ṣé agbatẹru ifilọlẹ yìí labẹ́…
Ìjọba Nàìjíríà Yóò Ríi Dájú Pé Àwọn Àgbẹ̀ Ní Àǹfààní Sí Okòwò Àti Ọjà Tó Yanrantí
Ìjọba Nàìjíríà sọ pé àwọn Agbẹ Ìgbèríko yóò ní àǹfààní sì Ọjà RAAMP fún kára káta lórí èrè oko wọ́n láti jẹ́ kí ìgbé ayé dẹrùn fún wọn àti láti dẹkùn òfo lórí ìkórè wọ́n.
"Àǹfààní pọ ni janturu fún wọn, pápá…
Minisita Ní Nàìjíríà Yóò Ríi Owó tótó Bílíọ̀nù Méjìdínlógún Náírà Nínú Ìfìmọ̀ṣọ̀kan Akáà
Minisita Ọgbin ati Ìdàgbàsókè Ìgbèríko, Dọkítà Mohammad Abubakar jẹ́ kó di mímọ pé Nàìjíríà yóò jèrè ti ótó Bílíọ̀nù Méjìdínlógún Náírà lórí Akáà mọkàndínlógún àládání pẹ̀lú Ìfìmọ̀ṣọ̀kan wá.
Minisita Ní ìjọba…