Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GBÌN

Àwọn Àgbẹ̀ Òní kòkó Ti Ìpínlẹ̀ Ondo Fí Ẹ̀dun Ọkàn Wọn Hàn Látàrí Bí Àwọn Onísé Láabi Ṣe N Dá Wọn…

Àwọn àgbẹ̀ ọ̀gbìn kòkó ni ìpínlẹ̀ Ondo ni agbègbè Odigbo ni oko ti wọn pe Oluwa Forest ,ti fi ẹ̀dun ọkàn  wọn ní hàn látàrí bi àwọn oníṣe láabi se n dá wọn Láàmú ninu oko Wọn ní àkolù yìí bẹ̀rẹ̀ láti ìgbà tí ilé ẹjọ ti ṣe ìdájọ lori ìja…

Ilé iṣé Ìjọba Ti Ìpínlẹ̀ Kwara Se Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ Fún Awọn Àgbẹ̀ Nípa Ọ̀gbìn Ẹ̀gẹ́.

Ó lẹ ní àádọ́ta àwọn àgbẹ̀ àti àwọn ènìyàn tí ó kópa nínú ìdánilékòó nípa ẹ̀gẹ́ gbin gbìn èyí wáyé láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ounjẹ ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ilé iṣé Ìjọba fún ètò ọgbin àti oúnjẹ ní o ṣe agbáterù ètò náà àti ìbáṣepọ̀ ìjọba…

Ẹgbẹ́ Àwọn Àgbẹ̀ Rọ Ìjọba Láti Ní Ìbáṣepọ̀ Pẹ̀lú Àwọn Tọrọ Kán Fún Ààbò Tó péye Lórí Oúnjẹ.

Gbogbo ẹgbẹ́ àwọn àgbẹ̀ ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí rọ ìjọba àpapọ̀ láti ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú ilé ìṣẹ́ ìjọba nípa ohun ọ̀gbìn àti láti ṣe ètò ààbò lórí oúnjẹ. ọ̀mọ̀wé Fẹmi Oke, to jé alága fún ẹgbẹ́ náà ló sọ èyí ni ọjọ́rú ni ìlú Eko, nigba…

Ẹgbẹ́ NACP Gbóríyìn Fún Ìjọba Àpapọ Lórí Owó Ìrànlọ́wọ́ Epo Rọ̀bì.

Ẹgbẹ́ NACP to jẹ ẹgbẹ́ ohun ọ̀gbìn ti Gbóríyìn fún ìgbésẹ Ààrẹ Bọla Tinubu gbé lórí owó ìrànlọ́wọ́ epo rọ̀bì, o wà fí ànfààní náà, bẹ̀bẹ̀ wí pé kó ṣe ètò ààbò pípẹ́ fún àwọn àgbẹ̀ lákọ̀kọ̀ọ́ ti won ba wa nínú oko láti sí ṣẹ.  Ọ̀rọ̀ yìí…
button