Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌLERA

This is a category for health news

Ẹgbẹ́ Ọmọ Ìlú Eko Ṣetán Láti Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Ètò Ìwòsàn Ọ̀fẹ́ Fún Ẹgbẹ̀rún Márùn-ún Àwọn Ènìyàn Ni…

Awọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọn gbé ni òkè òkun, ti orúkọ ẹgbẹ náà jẹ Ọmọ Ìlú Eko, ní àwọn ti ṣetán láti ran àwọn ènìyàn ẹgbẹrun marun-un lọwọ fún ìwòsàn ọfẹ kakakiri agbègbè ìlú Eko. Nígbà tí wọn ń sọ̀rọ̀ níbi ayẹyẹ àyájọ́ ọjọ́…

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Eko Ní Èróngbà Látí Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Fún Àwon Ènìyàn Tó Tó Mílíọ́nù…

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Eko sọ wí pé o kéré jù àwọn ènìyàn tó tó Mejidinlogun Mílíọ̀nù ni yóò gbà abẹ́rẹ́ àjẹsára láti dènà àrùn rọmọlápárọmọlẹ́sẹ̀, ètò yìí  yóò wáyé ní ọjọ́ kankan dilogun oṣù mẹwàá 2024. Dókítà Abímbólá Bowale, to jẹ akọwe fún…

Ìpínlẹ̀ Niger Mú  Àtúnṣe Àti Ìdàgbàsókè Bá Àwọn Ilé Ìwòsàn Káàkiri Àwọn Ijọba Ìbílẹ̀ Náà 

Nínú èròngbà láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ìlera káàkiri ìjoba ìbílẹ̀ márùn-únlélógún tó wà ní ìpínlẹ̀ Niger. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà ti bẹrẹ àwọn àtúnṣe nlá sí àwọn ilé ìwòsàn to wa láwọn ìjọba ìbílẹ̀ náà fún ìdàgbàsókè tó péye. Ìyàwó Gómìnà…

Ènìyàn Leè, Ṣe ìtọ́jú Àìsàn Ìtọ̀ Suger Nípa Jíjẹ Oúnjẹ Tó Sara Lóore: Àwọn Onímọ̀ Nípa Oúnjẹ.

Onímọ̀ nípa oúnjẹ jíjẹ, Ìyáàfin Ifeoluwa Akinyinka, ti gba àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lámọ̀ràn láti rí wí pé wọn n jẹ àwọn oúnjẹ tó ṣe ará lóore lọpọ ìgbà  Ó ní ipá àwọn oúnjẹ tó ṣe ará lóore wọnyi yóò dènà àìsàn ìtọ̀ Suger àti…
button