Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÁNILÁRAYÁ

This is a category for entertainment news

Ìgbẹkẹ̀lé Nínú Àwọn Ọ̀dọ́ Se Pàtàkì Fún Ìdàgbàsókè Àwùjọ- Onaiyekan Pàrọwà Sí…

Cardinal John Onaiyekan tí ó jẹ́ alàgbà ìjọ Kátólììkì ẹka ti Abuja ti rọ àwọn olósèlú láti rí ìgbẹkèlé nínú àwọn ọ̀dọ́ gẹ́gẹ́ bí okùnǹfà fún ìdàgbàsókè àwùjọ   Ó sọ ọ̀rọ̀ náà fún àwọn oníròyìn…

Àmójútó Àṣà Àti Ohun Ìsẹ̀ǹbáyé Yóò Mú Ìgbòòrò Bá Ọrọ̀ Ajé- Kọmísọ́nà Tẹ́lẹ̀rí

Kọmísọ́nà tẹ́lẹ̀rí Fún  Ìbára-ẹni-sọ̀rọ̀ Àti Àṣà ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ajagun fẹ̀yìntì Ibrahim Bata Malgwi Haruna ti sọ pé, Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ànfààní láti lo Àṣà àti àwọn Ohun ìṣẹ̀ǹbáyé rẹ̀…
button