Ọmọ ẹgbẹ́ agbaboolu Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Alex Iwobi ti rawọ ẹ̀bẹ̀ sí àwọn olólùfẹ̀ rẹ láti ní sùúrù to pọ fún àwọn,
wọn ní àwọn yóò sa gbogbo agbara awọn láti rí wí pé àwọn kópa nínú ìdílé bọọlu àgbáyé ti ọdún 2026.
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ko ni Ànfààní lati kópa ni ọdún 2022 ni Orílẹ̀-èdè Qatar, látàrí wí pé wọn ṣe dada to lórí pápá.
Leave a Reply