Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ

This is a category for business news

Ilé-Iṣẹ́ NNPCL Ná bílíọ̀nù kan dọ́là Lóri ríri òpó gígùn epo rọ̀bì mọ́ lẹ̀ ní Ajaokuta-Kaduna-Kano

Ilé-Iṣẹ́ Epo Rọ̀bì Lórílẹ̀dè Nàíjíríà, (NNPC) sọ pe awọn ti ná owó tó lé ní bílíọ̀nù kan dọ́là owó ilẹ̀ òkèrè lori òpó rírì ti nlọ lọwọ ní Ajaokuta-Kaduna-Kano, (AKK Gas Pipeline) ati iṣẹ ibudo. Olùdarí àti Alase Ilé-Iṣẹ́ NNPC, GCEO,…

Násáráwá: Ààrẹ Bùhárí yóò ṣe ìfilọ́lẹ̀ epo wíwà ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí yóò ṣe ìfilọ́lẹ̀ Epo wíwà nínú ilẹ̀ Ebenyi-A, ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun,ọjọ́ kejìdín-lọ́gbọ́n,oṣù Ẹrẹ̀ná, 2023 ní ìjọba ìbílẹ̀ Obi,ti ìpínlẹ̀ Násáráwá. Bí ààrẹ yóò ṣe ṣe ìfilọ́lẹ̀…

Nàìjíríà Àtí Íńdíà Ṣe Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Lórí Ìwádìí Ìmọ-jinlẹ̀ Ojú-ọjọ́ Àtí Ìdàgbàsókè

Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ìjọba orílẹ̀-èdè India tí fọwọ́ sí ìwé àdéhùn (MoU) fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí iṣẹ́ ìmọ-jinlẹ̀ ojú-ọjọ́, ìwádìí ìmọ-ẹrọ àtí ìdàgbàsókè. Àdéhùn náà ní a fọwọ́ sí ní orúkọ Ilé-iṣẹ́ Oju-ọjọ Nàìjíríà (NiMet)…
button