Orílẹ̀-èdè Chad tí gbẹ̀sẹ̀ lé gbogbo àwọn òun-ìní, ẹ̀tọ́ àti àwọn òun mère-mère mìíràn, tí Exxon Mobil (XOM.N), ilé-iṣẹ́ èpò orílẹ̀-èdè náà sọ nínú àlàyé kàn.
Exxon Mobil sọ nínú Oṣù Kejìlá pé òún títà àwọn ilé ìṣẹ́ rẹ̀ tó wà ní Chad àtí Cameroon fún ilé iṣẹ́ London kàn Savannah Energy (SAVES.L) pẹ̀lú àdéhùn irínwó lé díẹ̀ mílíọ̀nù dọla $407m, ṣùgbọ́n ìjọba Chadian takò àdéhùn náà, pé wọ́n kó pá òfin àwọn mọ́ ní ìgbẹ́yìn.
Orílẹ̀-èdè náà sọ pé òún lè gbé wọ́n lọ́ ilé-ẹjọ́ látí gbẹ̀sẹ̀ lé Ilé-iṣẹ́ náà l’ojuna látí dáàbòbo ẹ̀tọ́ rẹ̀, èyí tí yóò ṣé idiwọ fún Savannah lá tí rá áwọn òun-ìní Exxon Mobil ní orílẹ̀-èdè náà.
Tún kà nípa: ExxonMobil Gbá Ìwé Àdéhùn Wíwá Èpò Ni Ìlú Egypt
Exxon Mobil ní ipín ogójì 40% nínú iṣẹ́ àkànṣe èpò Doba tí orílẹ̀-èdè Chad, èyítí o ń ṣé àpapọ̀ èpò 28,000 (bpd) ní ọjọ́ kàn.
Làkókò ìròyìn yìí, Exxon Mobil àtí Savannah Energy kó tí fí ààyè sílẹ̀ fún ìbéèrè.
Leave a Reply