Take a fresh look at your lifestyle.

Rògbòdìyàn Russia-Ukraine Ní Yóò Kópa Nlá Níbí Ìpàdé G20

Lekan Orenuga

1 496

Rògbòdìyàn láàárín Russia àtí Ukraine ní yóò jẹ́ apakan pàtàkì tí wọ́n yóò jíròrò lè lórí níbí ìpàdé àwọn Mínísítà ilẹ̀ òkèèrè G20, ṣùgbọ́n India tó jẹ́ olugbalejo ṣé ìdánilójú náà látí ẹnu Mínísítà ilẹ̀ òkèèrè Vinay Kwatra pé, àwọn itanilaya tí ògún náà fà lórí eto-ọrọ àjé náà yóò gbà àkíyèsí dọgba-dọgba, akọ̀wé ilẹ̀ òkèèrè tí Orílẹ̀-èdè India sọ ní Ọjọ́bọ̀.

Ogójì àwọn Mínísítà ilẹ̀ òkèèrè ní yóò wà níbí ìpàdé náà pèlú Mínísítà ilẹ̀ òkèèrè Orílẹ̀-èdè Russia Sergei Lavrov, Akọ̀wé tí Ìpínlẹ̀ Orílẹ̀-èdè America Antony Blinken àtí Mínísítà ilẹ̀ òkèèrè Orílẹ̀-èdè China Qin Gang.

Lẹyìn ìkíni káàbọ̀ ní Ọjọ́rú, ìjíròrò yóò wáyé ní Ọjọ́bọ̀.

Tún kà nípa:Putin Yóò Sàlàyé Fún Àwọn Ìgbìmọ̀ Orílẹ̀-èdè Russia Nípa Ìjà Tó Ńlọ Lọ̀wọ̀ Ní Orílẹ̀-èdè Ukraine.

G20 pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè Orílẹ̀-èdè ọ̀lọ̀rọ̀ G7 bí Russia, China, India, Brazil, Australia àti Saudi Arabia, láàrín àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn.

Ó tún ṣeéṣe kí ifagagbaga ṣẹ̀lẹ̀ láàárín Orílẹ̀-èdè America atí China náà wáyé níbi ìpàdé náà, owó nínà Crypto àtí ìwà ipaniyan làgbáyé.

1 Comment
  1. […] Tún kà nípa:Rògbòdìyàn Russia-Ukraine Ní Yóò Kópa Nlá Níbí Ìpàdé G20 […]

Leave A Reply

Your email address will not be published.