Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ

This is a category for business news

Ilé Iṣẹ́ Bua Gé Owó Sìmẹ́ǹtì Lọ Sílẹ̀ Ṣí Ẹgbẹrún Mẹ́ta Ààbọ̀ Náírà

Ile iṣẹ to n se cement -BUA ni alẹ́ àná kéde lílọ sílẹ̀ iye owó ti wọn ń ta Sìmẹ́ǹtì láti ẹgbẹ̀run màrún/mẹ́fà sí Ẹgbẹ̀rún Mẹ́ta Ààbọ̀ Náírà fún báàgì kan láti òní lọ. Nínú akọsilẹ kan ti awọn alábójútó ilé ìṣẹ́ buwọ́lù, wọn sì gée, wọn…

Nàìjíríà Pẹ̀lú Àjọ Yúrópù Yóò Ṣé Àjọṣepọ̀ Lórí Ìlànà Ètò Ọrọ̀-àjé

Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Ajọ Yúrópù (European Union, EU) tí ṣé ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí ọrọ̀-ajé gẹ́gẹ́ bí ará àwọn akitiyan láti ṣé àtìlẹ́yìn ìyípadà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lórí ètò ọrọ̀-àjé. Èyí yóò ṣé ìrànlọ́wọ́ fún…

Mínísítà Olú-ìlú Nàìjíríà Gbèrò Látí Máà Ló Owó Tí Ilé-iṣẹ́ Náà Pá Fún Àwọn Iṣẹ́ Àkànṣe

Mínísítà tí Olúìlú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Abuja, Nyesom Wike tí kéde pé láti àkókò yíì, àwọn owó tí wọ́n bá pá lábẹ́lé (IGR) ní wọ́n yóò máa ló fún àwọn iṣẹ́ àkànṣe kàn. Mínísítà náà sọ làkókò tó ń ṣàlàyé àwọn ìgbésẹ̀ akin látí ṣé àtúnṣe…

Ilé Ìfọwópamọ́ Àpapọ̀ Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Owó Yiyá Fún Ilé Ìfowópamọ́ Tó Ń Ba Ní Kólé Owó Tó Lé Ní Biliọnu…

Ilé Ìfọwópamọ́ Àpapọ ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣe ìrànlọ́wọ́ owó tó lè Biliọnu Metadinlogoji Náírà fún ilẹ Ìfowópamọ́ tó n ba ni kólé ni ọdún 2022 ni èyí tí o farahàn ní nínú àkọsílẹ̀ ilé Ìfowópamọ́. Wọn ní yíyan owó àti di dá pàdà…
button