Browsing Category
ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ
This is a category for Africa news
Mínísítà Pè Fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Láàrin Àjọ ECOWAS Lójúnà Àti Gbógunti Àwọn…
Mínísítà Fún Ilẹ̀ Òkèèrè, Ambasadọ Yusuf Maitama Tuggar, tí ó jẹ́ alága ìpẹ̀tùsááwọ̀ fún àjọ ECOWAS ti pè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láti tán ìsòro àwọn alákatakítí, jàǹdùkú, ìwà ọ̀daràn lẹ́nu ibodè láàrin…
Ìjọba France Kó Ọmọ Ogun Kúrò Ní Orílẹ̀-èdè Chad
Ìjọba Orílẹ̀-èdè France ti bẹ̀rẹ̀ láti máa kó àwọn ohun èlò ìjagun èyí tí ó ti wà fún ọjọ́ pípẹ́ ní Orílẹ̀-èdè Chad kúrò látàrí àsọyépọ̀ ti o waye nípa àsìkò ti Orilẹ-ede France yoo fi se ìrànlọ́wọ́ fún…
Ìjọba Orílẹ̀-èdè Turkey Gbé Ìgbésẹ̀ Ìpẹ̀tùsááwọ̀ Láàrin Adarí Somalia Àti Ethiopia
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Turkey, Tayyip Erdogan ti sèpàdé ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ pẹ̀lú Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Somalia àti Ethiopia látàrí aáwọ̀ tí ó wà láàrin wọn lórí ààlà ilẹ̀, èyí tí ó wáyé ní ọjọ́rú. Ìgbésẹ̀ akin náà wáyé…
Ariwo Ẹ Gbálé Gbáta Gbòde Ní Orílẹ̀-èdè Ghana
Ikọ̀ kan ti wọn n pe ni Buz Stop Boys ni Orílẹ̀-èdè Ghana ti mórílé ojú pópó pẹ̀lú ìgbálẹ̀ àti àwọn ohun ìsèmótótó míràn láti se àmójútó àyíká jákè-jádò Orílẹ̀-èdè Ghana
Àwọn gbajúgbajà…
Ẹgbẹ́ Òṣèlú BDP Tó Ń Se Ìjọba Lọ́wọ́ Fìdí Rẹmi Nínú Ètò Ìdìbò Ni Orílẹ̀-èdè Botswana
Ẹgbẹ́ Òṣèlú Botswana Democratic Party (BDP) ti fìdí rẹmi ninu idibo ọ̀pọ̀ ile asofin ti ọsẹ yíì bi iroyin aladani iwe ìròyìn Mmegi se sọ ati ti ẹ̀rọ asọ̀rọ̀má- gbèsì ti ipinlẹ to gbe èsì ìbò lati bíi ìlàjì Konsituensi jade.…
Ilé Ejọ́ ECOWAS Ni Ààre Tuntun
Ilé ejọ́ agbegbe ECOWAS ti yan ààrẹ tuntun miran, Ricardo Gonçalves lat ilẹ̀ Cape Verde.
A yan fún ijoba ọdún méjì ni ofiisi láti ọwó àwọn adájọ marun ile ẹjọ.
Gonçalves, tẹ̀lé Ọ́nárébù adajo Edward Amoako Asante to ti lo…
Orilẹ̀-èdè Egypt : Ìjàmbá Ọkọ̀ Bọ́ọ̀sì Pa Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Akẹ́ẹ̀kọ́ Ifáfitì
Ọkọ̀ Bọ́ọ̀si to ko ọpọlọpọ akẹ́kọ̀ọ́ Ifáfitì
ni Ariwa ila oorun Egipti ti ni ijamba tó sì pa eniyan méjìlá ti mẹtalelọgbọn sí farapa bi eleto ìlera se sọ.
Àwọn akékòó náà n ti yara ìkàwé wọn bọ pada wa sí ayé wọ́n ki isele to…
Ọmọ Ọba Aládé Ilẹ̀ Sáúdí Yóò Se Àbẹwò Sí Ìlú Cairo
Ọmọ Ọba Aládé Ile Sáúdí, Mohammed bin Salman is yóò Se Abewo si ilẹ Cairo lati se iforowero nípa ètò òrò ajé ati ọrọ nipa rogbodiyan laarin Lebanon àti Gaza pelu aare Egipti, Abdel Fattah al-Sisi.
Igba keyin ti ọmọ oba alade…
Orílẹ̀-èdè Chad: Ìkún Omi Sọsẹ́ Fún Ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ Ènìyàn
Agbègbè tó lé lógún ní orilẹ-ede Chad ni àrọ̀ọ̀dá Òjò ti sọsẹ́ tó sì ti fa ìkún omi tó lágbára, orilẹ̀-èdè níbití rògbòdìyàn oúnjẹ ti ń ṣẹlẹ̀ tẹ́lẹ̀ lemọ́lemọ́.
Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta ènìyàn ló ti ta téru nípàá, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹbí ló ti di…
Ààrẹ Senegal Kéde Ọjọ́ Ìdìbò Oṣù Kẹ́ta
Ìjọba orílẹ̀-èdè Senegal ti kéde pé idibo sí ipò ààrẹ yóò wáyé ni ọjọ kẹrìnlélógún oṣù keta.
Ikede yi ri bẹẹ latari awuyewuye isunsiwaju ti ààrẹ Macky Sall ti kọkọ se losu to koja, to fa iwode to tan kaaakiri bí ina igba ẹ̀rùn…