Ọmọ Ọba Aládé Ile Sáúdí, Mohammed bin Salman is yóò Se Abewo si ilẹ Cairo lati se iforowero nípa ètò òrò ajé ati ọrọ nipa rogbodiyan laarin Lebanon àti Gaza pelu aare Egipti, Abdel Fattah al-Sisi.
Igba keyin ti ọmọ oba alade Sáúdí to tun nje “MbS” ti sabewo keyin si Egipti ni ọdún 2022..
Ààre ilè Egipti sọ ni oṣù to koja pé ile Saudi Arabia n gbiyanju láti dokòwò Biliọnu marun Dola sí Egipti.
Ẹrọ mohunmaworan ti ilelẹ̀ Sáúdí ti fi idi otitọ múlẹ pé ọmọ oba alade Sáúdí ti gbera lọ sí Egipti lai sọ gbogbo eyi toku to yẹ.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san