Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé Ejọ́ ECOWAS Ni Ààre Tuntun

436

 

Ilé ejọ́ agbegbe ECOWAS ti yan ààrẹ tuntun miran, Ricardo Gonçalves lat ilẹ̀ Cape Verde.

A yan fún ijoba ọdún méjì ni ofiisi láti ọwó àwọn adájọ marun ile ẹjọ.

Gonçalves, tẹ̀lé Ọ́nárébù adajo Edward Amoako Asante to ti lo ọdun mefa ninu isejoba lati ọ̀kànlélọ́gbọ̀n , osu keje odun 2018.

Bakanna, wọn yan adajo.Mohamed Koroma, lati orilẹ-ede Sierra Leone gégé bí igbakeji rẹ to tẹle adajo Gberi-bè Ouattara, lati ilẹ Ivory Coast.

Níbi oro akoso ifinijoye rẹ, adájọ Ricardo Claúdio Monteiro Gonçalves sọ èròngbà rẹ fún ile ẹjọ to da lori nǹkan meji-ìfọmọnìyànse àti ìfọ̀rọ̀wérò.

Àwọn Adajo meta ile ẹjọ náà ni wọnyi:
Adájọ Edward Amoako Asante (Ghana), aare to n kogba sile, Adájọ Gberibè Ouattara (Côte d’Ivoire) ati Adájọ Dupe Atoki(Nigeria).
 

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

 

Comments are closed.

button