BBTitans: Blaqboi Di Olórí Ilé Tuntun
Méjì nínú àwọn alábágbélépọ̀ ti Big Brother Titans, Ipeleng àti Blaqboi ti di olórí ilé tuntun alájọsepọ̀ ti eré
ìgbéwò òdodo tó ń lọ lọ́wọ́.
Bí eré náà se ń parí lọ, ìdíje olórí ilé náà ń le síi, gbogbo olùkópa ló ń múra láti…