Take a fresh look at your lifestyle.

Ìbò Ààrẹ Ọdún 2023, Ó Ní Agbára-Ilé Ààrẹ

0 88

 

Ìbò Ààrẹ tó wáyé ní ọjọ́ karùn-dín- lọ́gbón, oṣù Kejì, ọdún 2023 jẹ́ ìbò tó lágbára tí kò sí irú rẹ̀ nínú ìtàn orílẹ̀-èdè yìí.

 

Nínú ìwé ìfiránṣẹ́ tí wọ́n kọ, Olùdámọ̀ràn pàtàkì fún ààrẹ lórí ọ̀rọ̀ ètò ìròyìn àti ìfiléde, Garba Shehu jẹ́ kó di mímọ̀ pé ìbò náà kò dẹrùn, pé àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè yìí tí yan ẹni tí wọ́n fẹ́ tí yóò ṣe ìjọba lé wọn lórí lēyìn Ààrẹ Buhari.

 

Ó dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn alāmójútò láti òkè òkun fún iṣẹ́ ribiribi wọn tí wọ́n se.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave A Reply

Your email address will not be published.