Browsing Category
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
This is a category for politics news
APC kọ ẹsun ti PDP fi kan an lori gomina ipinlẹ Imo
Akọ̀we ìpolongo àpapọ̀ ti ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC, Ọ̀gbẹ́ni Felix Morka ti bẹnu àtẹ́ lu ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party, PDP fún ohun tí wọ́n ṣàpèjúwe rẹ bíi “Àìwúlò pátápátá.”
Ẹgbẹ oṣelu…
Àṣeparí ìdìbò gómìnà : Alága INEC rọ àwọn òṣìṣẹ́ elétò ìdìbò láti ṣe iṣẹ́ wọn…
Alága ìgbìmọ̀ olómìnira tó ń mójútó ètò ìdìbò lórílẹ̀-èdè, INEC, Ọ̀jọ̀gbọ́n Mahmood Yakubu ri rọ àwọn òṣìṣẹ́ ìgbìmọ̀ náà láti ṣàfihàn bí wọ́n ṣe nífẹ̀ẹ́ orílẹ̀-èdè wọn àti ìmọṣẹ́ wọn bíi iṣẹ́.
O pe…
Yíyí Orúkọ Ilé ìwe Gíga Ètò Ìkọ́ni Ti Ìlú Okene Padà Sí Orúkọ Olóògbé Ọba Alayé…
Sẹ́nétọ̀ Natasha Akpoti-Uduaghan tí ó n sojú ààrin gbìngbìn ìpínlẹ̀ Kogi ti se ìfiléde àbádòfin kan èyí tí ó ń pèpè fún sísọ orúkọ olóògbé ọba alayé, Ọ̀mọ̀wé Ado Ibrahim di málegbàgbé pẹ̀lú yíyí orúkọ…
Ọ̀gá Àgbà Àpapọ̀ Fún Àjọ Ọlọ́pàá Ti Pàṣẹ Ìsípòpadà Kọmísọ́nà Àjọ Náà Ní Ìpínlẹ̀…
Ọgá Àgbà Àpapọ̀ Àjọ Ọlọ́pàá, Kayọde Ẹgbẹtokun ti pàṣẹ ìsípòpadà alákòóso àjọ náà ní ìpínlẹ Imo, Ọgbẹni Mohammed Barde sí ọ́ọ́fìsì àpapọ̀ àjọ náà ní ìlu Abuja.
Ọ̀rọ̀ náà wáyé nínú ìfiléde…
Rògbòdìyàn ìpínlẹ̀ Rivers: Gómìnà Fubara dúpẹ́ lọ́wọ́ ààrẹ Tinubu fún dídásí rẹ̀
Gómìnà ìpínlẹ̀ Rivers, Siminalayi Fubara ti fi ọpẹ́ rẹ̀ hàn sí ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu fún “ìdásí àgbà” nínú rògbòdìyàn olóṣèlú tó wáyé ní ìpínlẹ̀ náà láìpẹ́ yìí.
Ninu alaye kan ti funra rẹ buwọlu ti o…
Ìkọlù Ẹgbẹ́ Òṣìṣẹ́ Ní Ìpínlẹ̀ Imo: Gbajugbaja Nínú Ẹgbẹ́ Òṣèlú NNPP Ke Sì Àwọn Agbófinró Láti Fi Ojú…
Gbajúgbajà nínú ẹgbẹ́ òṣèlú NNPP tó tún jẹ́ bàbá isalẹ fún ẹgbẹ́ Akọ̀ròyìn ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ (Oyo State Correspondents' Chapel) Olufemi Ajadi Oguntoyinbo tí korò ojú sí ìkọlù sí Ààrẹ ẹgbẹ́ oṣiṣẹ Joe Ajero lásìkò tí òun àti ẹgbẹ́ oṣiṣẹ ni…
Ilé Asòfin Èkó ṣe àtúnṣe sí Òfin Ètò Ìṣúná-owó ọdún 2023
Ile Igbimọ Asofin Ipinlẹ Eko labẹ Oludari Ile, Aṣofin Mudashiru Ọbasa ti ṣe atunṣe si Ofin Eto Iṣuna-owo ọdun 2023 fun Ipinlẹ Eko, eleyii ti o faaye gba ṣiṣe atunto fun inawo Biliọnu lọna mọkan-le-lọta-le-ẹẹdẹgbẹrin ati…
Alága àpapọ̀ APC yan SSA tuntun fún ìdánilẹ́ékọ́ ará ìlú
Alága àpapọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, APC, Dókítà Abdullahi Umar Ganduje ti yan àgbà akọ̀ròyìn, Olóyè Oliver Okpala gẹ́gẹ́ bí àgbà igbákejì pàtàkì rẹ̀ fún ìdánilẹ́ékọ́ ará ìlú.
Iṣẹ rẹ si ti…
Àwọn tó niíṣe rọ INEC fún ìdìbò gómìnà otitọ ní Bayelsa, Imo, Kogi
Àwọn tó niíṣe rọ Ìgbìmọ̀ olómìnira tó ń mójútó ètò ìdìbò lórìlẹ̀-èdè (INEC), láti ríi pé ìdìbò gómìnà ọjọ́ kọkànlá, oṣù kọkànlá ní Bayelsa, Imo àti Kogi lọ nírọ̀wọ́ rọsẹ̀, lótìítọ́ àti léyìí tó…
Alága Ẹgbẹ́ Òsèlú APC Sèdárò Ikú Ohinoyi Ti Ilẹ̀ Ebira
Alága Àpapọ̀ Ẹgbẹ́ Òsèlú APC Abdullahi Umar Ganduje ti fi àìdùnnú ọkàn hàn lórí ìpapòdà Ohinoyi ti ilẹ̀ Ebira, Alayélúwà, Alhaji Ado Abdulrahaman Ibrahim
Ìròyìn fi yéwa pé ọba alayé náà jáde láyé…