Browsing Category
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
This is a category for politics news
Kọmísọ́nà Fún Ìpínlẹ̀ Ebonyi Gbóríyìn Fún Ìdàgbàsókè Tó Wáyé Láàrin Ìlú Láti Ọwọ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀…
Kọmísọ́nà fún ìbílẹ̀ àti agbègbè olóyè Uchenna Igwe ti Gbóríyìn fún ìdàgbàsókè àti ìlọsíwájú tó ṣẹlẹ nínú ìlú láti ọwọ́ Gómìnà ìpínlẹ̀ náà Francis Nwifuru.
Kọmísọ́nà sọ èyí di mímọ̀ níbi ìpàdé ìlú tí o wáyé ni Obegu Azuiyokwu pẹ̀lú àwọn…
Edo 2024: Olùdíje ipò gómìnà pinnu láti ra abala ètò ẹ̀kọ́ padà
Olùdíje ipò gómìnà fún ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party, PDP ní ìpínlẹ̀ Edo, Ọ̀gbẹ́ni Anslem Ojezua, ti sọ pé òun yóò ra abala ètò ẹ̀kọ́ padà tí òun yóò sì tún ṣe àmójútó ìgbé ayé àlàáfíà àwọn…
Gómìnà Gúsù Àríwá fẹnu kò lórí Àgbákalẹ̀ tuntun
Ìgbìmọ̀ àwọn Gómìnà Gúsù Àríwá ní Nàìjíríà, NEGF, ti túnbọ̀ fẹsẹ̀ ìpinnu rẹ̀ láti fún gbogbo ọmọ ìlú láǹfààní àti láti pèsè ètò ààbò, ìbáraẹniṣepọ̀ àti àkójọpọ̀ ètò ọrọ̀-ajé ní ẹkùn náà…
Adarí Ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Kaduna kí Gómìnà Uba Sani kú oríire
Adarí Ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin Ìpínlẹ̀ Kaduna ẹlẹ́ẹ̀kẹsàn án, Aṣòfin Yusuf Zailani ti kí Gómìnà Uba Sani kú oríire lórí àṣeyọrí rẹ̀ ní ilé-ẹjọ́ kò tẹ́mi lọ́rùn.
Ninu alaye kan ti oluranlọwọ pataki rẹ lori eto…
Ẹgbẹ́ Òsèlú APC Se Ìwọ́de Ní Ìpínlẹ̀ Kano
Ẹgbẹ́ Òsèlú APC ti fi ìdí ìgbáradì rẹ̀ múlẹ̀ fún ìwọ́de ìta-gbangba tí ó wáyé ní ìlú Kano ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹgbẹ́ òsèlú NNPP lòdì sí ìgbésẹ̀ náà
Àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ nínú…
Gòmìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Àti Àwọn Alẹ́nulọ́rọ̀ Gbàdúrà Fún Amòfin Àgbà Ti Orílẹ̀-èdè…
Gómìnà Ìpínlẹ Kwara, AbdulRahaman AbdulRasaq pẹ̀lú àwọn asojú ìjọba , ní ọjó Ẹtì péjú sí ibi àkànse ìjókòó àdúrà fún amòfin àgbà tuntun fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó tún jẹ́ Mínísítà Fún Ìdájọ́…
Ilé Ẹjọ́ Kòtẹ́milọ́rùn Kò Fi Ìdájọ́ Sègbè, Ó Fi Ìdí Ìjáwé Olúborí Gómìnà Sule…
Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀ Nasarawa, Ọnọrébù Ibrahim Balarabe Abdullahi ti gbósùbà fún ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn tí ó wà ní ìlú Abuja, látàrí bí ó se fi ìdí ìjáwé olúborí Gómìnà Abdullahi Sule múlẹ̀…
Ààrẹ Tinubu Paná Rúkè-rúdò Tí Ó Ń Sẹlẹ̀ Ní Ìpínlẹ̀ Ondo
Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu gbé ìgbésẹ̀ akin láti paná aáwọ̀ tí ó ń sẹlẹ̀ ní ìpínlẹ Ondo kí àlàáfíà le è jọba ní ìpínlẹ̀ náà
Lẹ́yìn atótónu Ààrẹ, igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ náà, Ọ̀gbẹ́ni Lucky…
Gómìnà Méjì Tí Wọ́n Dìbò Yàn Sàbẹ̀wò Sí Aarẹ Tinubu
Gómìnà tuntun méjì tí wọ́n dìbò yàn ní ìpínlẹ̀ Kogi àti Imo, Usman Ododo àti Hope Uzodinma ti se àbẹ̀wò sí ààrẹ Tinubu láti se àfihàn ìwé ẹ̀rín wọn
Alága àpapọ̀ ẹgbẹ́ òsèlú APC, Abdullahi Ganduje…
Ilé Aṣòfin Èkó pe Àjọ tó ń gba Ọjà wọle fún ijoba lórí ẹ̀sùn ìnákúnàá owó…
Ile Igbimọ Aṣofin Ipinlẹ Eko ti pe Ajọ to n mojuto gbigba Ọja wọle si Ile-iṣẹ ijoba Ipinlẹ Eko lati wa wẹ ara wọn mo ̣fun ẹsun ti awọn kan fi kan ile-iṣẹ Gomina ati ti Igbakeji Gomina fun awọn owo kan ti wọn na, eyi ti ko…