Browsing Category
ÌRÒYÌN ÒSÈLÚ
This is a category for politics news
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara Ń Gbìyànjú Nípa Ìpèsè Òpópónà Tí Ó Yè Kooro Ní Àwọn…
Ọmọ Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin tí ó ń sojú fún ààrin gbìngbìn Ìpínlẹ̀ Kwara, Sẹ́nétọ̀ Saliu Mustapha ti juwọ́ káre sí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara, AbdulRahaman AbdulRasaq fún ìsàtúnse àti ìpèsè òpópónà tí ó yè kooro…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kogi Mú Àdíkù Bá Ìgbòkè-gbodò Ọkọ̀ Látàrí Ètò Ìdìbò Ọjọ́…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kogi ti se ìfiléde èyí tí kò fi àyègba ìgbòkè-gbodò ọkọ̀ laàrin agogo méje òwúrọ̀ sí agogo mẹ́rin ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ Àbámẹ́ta
Ọ̀gbẹ́ni Kingsley Fanwo tí ó jẹ́ kọmísọ́nà fún ìfọ̀rọ̀léde ni…
Ìdìbò Ìpínlẹ̀ Ondo: Àjọ Elétò Ìdìbò Ti Ń Pín Káàdì Ìdìbò.
Àjọ Elétò Ìdìbò ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sọ wí pé àwọn ti bẹ̀rẹ̀ pínpín Káàdì ìdìbò láti ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù mẹwàá.
Wọ̀n ní èyí wà fún igbaradi ìdìbò Gómìnà tí yóò wáyé ni ọjọ́ kerindinlogun oṣù kankonla ọdún 2024.
Alága fún àjọ…
Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Jẹ́jẹ̀ẹ́ Láti Tẹ̀síwájú Nínú Akitiyan Rẹ̀ Fún Ìdàgbàsókè…
Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin, Abbas Tajudeen ti sàfirinlẹ̀ ìgbáradì rẹ̀ láti tẹ̀síwájú nínú ìlàkààkà rẹ̀ fún ìdàgbàsókè àwọn obìnrin àti láti se ìrànlọ́wọ́ fún àwọn obìnrin tí ó wà nínú ètò òsèlú…
Nípa Ìdádúró Ìsúná Owó Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin: Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Pè Fún…
Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Adebo Ogundoyin ti pè fún ìtẹ̀síwájú ìfọ̀rọ̀-wérọ̀ láàrin ẹgbẹ́ àpapọ̀ àwọn ọmọ asòfin àti àwọn gómìnà láti mú àbádòfin tí ó pè fún àdáyanrí owó ìsúná àwọn…
Agbẹnusọ Àti Igbákejì Rẹ̀ Ní Ìpínlẹ̀ Bauchi Kọ̀wé Fipò Sílẹ̀
Agbẹnusọ Ati Igbakeji ni ile ìgbìmọ̀ aṣòfin Ipinle Bauchi Babayo Akuyam àti Ahmed Abdullahi ti kọwe fipo wọn sílẹ̀.
Akuyam (PDP – Hardawa State Constituency), ati Abdullahi (PDP – Dass State Constituency) ti kéde ikọwe fi ipò…
Ẹgbẹ́ Òṣèlú APC Sèdárò Ikú Alága Ẹgbẹ́ Ní Ìpínlẹ̀ Ekiti
Ẹgbẹ Oṣelu APC ipinle Ekiti ti sedaro ikú alaga ẹgbẹ, Paul Omotoso, ni ilu Ekiti, iwọ ooru Gusu orile-ede Nàìjíríà.
Akowe ati alukoro gbogbogbo ẹgbẹ, Felix Morka, Esq sọ nínú akọsilẹ kan pé, " Ki ilu to mulọ wẹ́rẹ́, Omotoso ti a bi láti…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Anambra Bá Ọ̀gagun Àti Ààrẹ Tẹ́lẹ̀ Rí Fún Orílẹ-èdè Nàìjíríà Olusegun Obasanjo Yajọ̀…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀mọ̀wé Chukwuma Soludo ti ba o ní ire yọ, iyen Ààrẹ Tẹ́lẹ̀ fún Orílè-èdè Nàìjíríà Ọ̀gagun Olusegun Obasanjo Yajọ̀ Ọjọ-ibi re láyè, lóni ọjọ́ karún osù keji Ọdún 2024
Gómìnà Soludo dupẹ púpọ lọwọ Ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí…
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ fi àwọn ẹgbẹ́ alátakò sílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ebonyi
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Grand Alliance, APGA, Labour, LP, áti People’s Democratic Party, PDP ní ìpínlẹ̀ Ebonyi ti fi ẹgbẹ́ wọn sílẹ̀ lọ darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ tí ń ṣèjọba All Progressives Congress, APC ní ìparí…
Àjọ Kan Gbósùbà Fún Àwọn Ọmọ Asòfin Látàrí Fífi Owó Osù Se Ẹ̀bùn Fún Ẹkùn Tí Wọ́n…
Àjọ (Civil Liberty Org.) ti gbóríyìn fún àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asòfin mẹ́jọ kan ní ìpínlẹ̀ Anambra nígbà tí wọ́n fi owó osù mẹ́fà se ìtọrẹ àánú fún àwọn ènìyàn ẹkùn tí wọ́n sojú fún
Ìtọrẹ àánú…