Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

Ó GBÓNÁ FẸLI-FẸLI

This is a category for LATEST NEWS

Ìpínlẹ̀ Oyo: Àwọn Amòfin gbé ìgbésẹ̀ láti fagilé lílo ẹ̀rọ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ alágbéká…

Ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin ti Ìpínlẹ̀ Oyo ti paá láṣẹ fún ìgbìmọ̀ ètò Ẹ̀kọ́ (Àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti Gíga) láti ṣèjíròrò pẹ̀lú àwọn tó níí ṣe àti láti ṣètò ọ̀nà láti gbé ìfagilé lílo ẹ̀rọ ìbaraẹnisọ̀rọ̀ alágbéká ní…

Ayẹyẹ Ọdún Ajinde: Ẹ Gbé Ìgbé Ayé Tó Bu Ọlá Fún Ọmọnìyàn – Aláàfin Ọ̀yọ́

Aláàfin Ọ̀yọ́, Ọba Abímbólá Akeem Owoade I, ti gba ọmọ orilẹ èdè Nàìjíríà níyànjú láti pawọ́pọ̀ gbógun ti ìtàjẹ̀sílẹ̀ àti gbogbo ẹni yìówù tó sọ ará rẹ̀ di ọ̀tá ìlú tó n pa ènìyàn ni ìpakúpa. Ọba Owoade, ẹni tó korò ojú si ìwà ìpànìyàn…

Ẹgbẹ́ àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ Nàìjíríà lókè òkun yan àwọn aláṣẹ tuntun

Ẹgbẹ́ àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ Nàìjíríà lápapọ̀ lókè òkun ti yan àwọn aláṣẹ tuntun tó pinnu láti jẹ́ aṣojú rere fún Nàìjíríà. Aarẹ ẹgbẹ naa Ọgbẹni Juwon Fayomi, ṣe ipinnu yii nibi ayẹyẹ ifilọlẹ ati Idanilẹkọ fun gbogbogboo…

Ààrẹ Tinubu ṣèdárò ikú ògbóhùntarìgì agbábọ́ọ́lù Nàìjíríà, Christian Chukwu

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti ṣèdárò pẹ̀lú ẹbí, ọ̀rẹ́ àti àwọn alájọṣepọ̀ ògbóhùntarìgì agbábọ́ọ́lù Nàìjíríà Christian Chukwu, tí ó di olóògbé ní ọjọ́ Àbámẹ́ta ní ọmọ ọdún mẹ́rìnlé-láàdọ́rin. Nigba ti o n…
button