Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ

This is a Nigeria news category

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Gombe Bá Àwọn Àrinrìn-àjò Hajj Ẹgbẹ̀rún dín-ní-ogójì-dín-méjì Yọ̀

Gómìnà Muhammadu Yahaya tí Ìpínlẹ̀ Gombe tí fí ọrọ ránṣẹ́ sí àwọn àrinrìn-àjò ẹgbẹ̀rún-dín-ní-ogójì-dín-méjì (962) tí wọ́n fẹ́ ẹ ṣé Ìrìn-àjò sí Makkah fún Hajj l'ọdún 2025, Saudi Arabia. ‎ ‎ Nígbàtí o n sọrọ níbí ayẹyẹ idagbere náà ní…

Ọ̀sẹ̀ Àṣà Ìlú Ìbàdàn Tí 2025: Makinde Ṣèlérí Láti Fún Àwọn Olórí Ìlú Ní Ẹ̀tọ́ Wọn.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti ṣèlérí pé ìṣèjọba òun kò ní fi ẹ̀tọ́ àwọn olórí ìlú dùn wọ́n. Gómìnà ló sọ ọ̀rọ̀ yii di mímọ̀ níbi àṣèkágbá ayẹyẹ ọsẹ̀ àṣà ìlú Ìbàdàn to wáyé ni pápá ìṣeré Obafemi Awolowo, ni agbègbè Òkè-Ado, ni ìlú…

Hajj 2025: Kwara gbé àwọn arìnrìn àjò mímọ́ ikọ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹta ti ẹdẹ̀ẹ́gbẹ̀ta-ó-lé-ọgọ́ta Lọ…

Ikọ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹta àwọn arìnrìn àjò mímọ́ tí ó tó ẹdẹ̀ẹ́gbẹ̀ta -ó -lé -ọgọ́ta láti ìpínlẹ̀ Kwara gbéra lọ sí Saudu Arabia ní ọjọ́ Àbámẹ́ta láti ṣe iṣẹ́ mímọ́, tí ó sì jẹ́ pé ọkọ̀ òfurufú Max ni ó gbé wọn láti…

Ààrẹ Tinubu túnbọ̀ fìdí ìpinnu rẹ̀ múlẹ̀ lóri ìfọ̀rọ̀jomitoro ọ̀rọ̀ láàrin ẹlẹ́sìn,…

Adarí Nàìjíríà, Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti túnbọ̀ fìdí ìpinnu rẹ̀ múlẹ̀ lóri ìṣàgbélárugẹ àjọṣepọ̀ ìfọ̀rọ̀jomitoro ọ̀rọ̀ láàrin Àwọn ẹlẹ́sìn, ìgbàmọ́ra, àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ jákèjádò lágbàáyé Ààrẹ naa…

Ètò Ìkànìyàn Ṣe Pàtàkì Fún Ìgbáradì Ọjọ́ Iwájú Nàìjíríà – Ààrẹ Sẹ́nètì

Ààrẹ àwọn Senetọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Sẹ́nétọ̀ Godswill Akpabio ti sọ pé ó pan dandan láti ṣe ètò Ìkànìyàn láti lè jẹ́kí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pèsè fún ọjọ́ ọlá èniyàn rẹ. Sẹ́nétọ̀ Akpabio sọ pé ó ye kí ètò ìkànìyàn náà ti wáyé…
button