Browsing Category
ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ
This is a Nigeria news category
NELFUND pín iye owó tó lé ní Bílíọ́nù mẹ́rìndínlọ́gọ́ta Náírà fún ẹ̀yáwó akẹ́kọ̀ọ́
Àjọ tí ń rísí owó yíyá fún ẹ̀kọ́ ní Nàìjíríà (NELFUND), ti kéde pínpín iye owó tó lé ní Bílíọ́nù mẹ́rìndínlọ́gọ́ta Náírà láìgba èlé fún àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga tíjọba jákèjádò orílẹ̀-èdè láti bí…
Àwọn Amòfin Fọwọ́ Sí Yíyan Gómìnà Ìpínlẹ̀ Katsina Lẹ́kàn Si
Àwọn Amòfin Fọwọ́ Sí Yíyan Gómìnà Ìpínlẹ̀ Katsina Lẹ́kàn Si
Àwọn amòfin láti ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Katsina ti fọwọ́ sì yíyan gómìnà Umar Radda fún ìgbà kejì ní orí àlééfà.
Ìbuwọ́lù náà wáyé láti ọwọ́ ẹgbẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú All…
Ìpínlẹ̀ Rivers Tún Jẹrìí Sí Ìtẹ̀síwájú Àwọn Òṣìṣẹ́
Ìjọba ìpínlẹ̀ Rivers ní Gúúsù-gúúsù Nàìjíríà tí ṣé àtúnṣe fún ìtẹ̀síwájú àwọn òṣìṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ náà nígbà tí wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ ètò àtúnṣe ilé-iṣẹ́ ìpínlẹ̀ Rivers.
Olùdarí Ìpínlẹ̀ Rivers, 'Vice Admiral' Ibok-Ete Ibas, ṣé ìpinnu ní…
Kó Sí Ẹnikẹ́ni Tó Ń Dárí Ààrẹ Tinubu Bò Tí Wù – Mínísítà
Mínísítà fún ìròyìn àti Àlàyé tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Mohammed Idris, tí kéde pé Aare Bola Tinubu kó sí lábẹ́ ipá èyíkéyìí àwọn alágbára Orílẹ̀-èdè, Ó tẹnumọ pé Ààrẹ ní òmìnira látí ṣé gbogbo àwọn ìpinnu pẹ̀lú àwọn ànfààní tó dára jùlọ fún…
Àṣeyọrí Àtúnṣe Ètò-ọrọ Àjé Ní Kí Ilé-iṣẹ́ NNPCL Gúnlè Fún Ìtẹ̀síwájú – Ààrẹ Nàìjíríà
Ààrẹ Bola Tinubu tí gbá àwọn ìgbìmọ̀ túntún fún ilé-ìfọpo Nàìjíríà (Nigerian National Petroleum Company Limited NNPCL) tó ṣé ìfilọ́lẹ̀ rẹ̀ gúnlè ìlọsíwájú tó ṣé nípasẹ àwọn àtúnṣe ètò-ọrọ àjé, èyítí o fí gbóríyìn fún Imúdára àti ìpèsè ayé…
Ó Lé Ní Ẹgbẹ̀rún Mẹ́talá Àwọn Oníjágìdíjagán Tí Á Tí Dá Lọ́wọ́ Kọ́ Láàrín Oṣù Kàrún 2023 Sí Ọdún Yìí…
Olùdámọ̀ràn Ààbò tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NSA), Mallam Nuhu Ribadu, tí sàlàyé pé ó lé díẹ̀ ní ẹgbẹ̀rún mẹ́talá àbọ̀ (13,543) àwọn oníjágìdíjagán àti àwọn afurasi ọdaràn mìíràn ní a tí dá lọwọ́ kọ́ yọ́ kúrò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti oṣù…
Ààrẹ Tinubu Ṣàfihàn Ìlọsíwájú Ẹgbẹ́ APC Sí Àwọn Àtúnṣe Ètò Ọrọ-àjé
Ààrẹ Bola Tinubu tí sọ pé àtìlẹ́yìn tó ń pọ̀ sí i fún ẹgbẹ́ òṣèlú 'All Progressives Congress' (APC) ló jẹ́ àṣeyọrí àgbàyanu tí ẹgbẹ́ náà ṣe láàárín ọdún méjì àkọ́kọ́ tí wọ́n ti lò lẹ́nu iṣẹ́ ìjọba, ó sì fi dá àwọn ọmọ Nàìjíríà lójú pé…
Ètò Ẹ̀kọ́: Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Rẹmi Tinubu Bèrè Anfààní Ẹ̀kọ́ Ọfẹ Fún Àwọn Ọ̀dọ́.
Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Oluremi Tinubu, sọ wí pé oun ṣiṣe lórí bí ètò ẹ̀kọ́ ọfẹ yóò ṣẹ wa fun àwọn ọ̀dọ́
Nígbà tí o ń ba aláṣẹ ilé iṣé MERCK Foundation sọ̀rọ̀, ilé iṣé ti o jẹ aláàdáni láti Orílẹ̀-èdè German nígbà tí wọn ṣe àbẹ̀wò…
Ọ̀jọ̀gbọ́n Soyinka Polongo Gbígbé Èdè Àbínibí Ilẹ̀ Wa Lárugẹ
Ọ̀jọ̀gbọ́n Wole Soyinka-"Nobel Laureate", ti tẹnumọ bó ṣe se pàtàkì láti gbé èdè abínibí ilẹ̀ wá àti àṣà òjogúnbá lárugẹ, wípé ó jẹ́ ohun ìwúlò pàtàkì fún ìdàgbàsókè orílẹ̀-èdè .
Ó sọ èyí ní ọjọ́ Ajé níbi ti o ti ń dáhùn ìbéèrè láti ọdọ…
Ipinlẹ Anambra Gbé Ìgbésẹ Akínkanjú Nípa Títún Àyíká Àti Bèbè Omi Ṣe.
Ìjọba ìpínlẹ̀ Anambra pẹ̀lú àjọsọpọ̀ - "Initiative for Agulu Development" ní ọnà láti ṣe ìmọ́tótó sì àwọn agbègbè ti omi wà àti àwọn àyíká rẹ àti ni ọ̀nà láti jẹ́ kí ẹ̀gbin omi dínkù, wọn ti ṣètò ìmọ́tótó ní gbogbo bèbè omi àti…