Browsing Category
ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ
This is a Nigeria news category
Ààrẹ Tinubu Kí Alága NRS Zacch Adedeji Ẹní Ọmọ Ọdún mẹ́tàdínlàádọ́ta
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti kí Alága fún Iṣẹ́ Owó-orí Nàìjíríà (NRS), Dókítà Zacch Adedeji, ní ayẹyẹ Ọjọ́ìbí rẹ̀, O gbóríyìn ìtọ́sọ́nà rẹ̀ lórí ìyípadà ilé-iṣẹ́ owó-orí orílẹ̀-èdè náà.
Nínú ìròyìn kán tí Agbẹnusọ Ààrẹ fi síta,…
Mínísítà Kẹ́dun Pẹ̀lú Àwọn Aráàlú Tó Pàdánù Àwọn Ènìyàn Nínú Ìkọlù Ìpínlẹ̀ Niger
Mínísítà fún Ìpínlẹ̀ fún Ise-ọgbin àti Ààbò Oúnjẹ tí Nàìjíríà, Aliyu Sabi Abdullahi, (Baraden Borgu), tí kẹ́dun pẹ̀lú àgbègbè Kasuwan Daji ní Ìjọba ìbílẹ̀ Borgu ní Ìpínlẹ̀ Niger lórí ikọlù tí àwọn oníjàgídíjàgan ṣé si agbègbè náà.
…
Igbákejì Ààrẹ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Pé Fún Ìṣọ́kan Àti Àjọṣepọ̀ Láàrín Àwọn Aláṣẹ Àti Aṣòfin
Igbákejì Ààrẹ Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Nàìjíríà, Sẹ́nétọ̀ Barau Jibrin, ti pe fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ tó lágbára àti ọ̀wọ̀ láàrin àwọn Aláṣẹ àti Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin, gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà pàtàkì láti mú kí ìjọba tiwantiwa ṣọ̀kan ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
…
ADC Ṣètò Ẹgbẹ́ Ìṣàtúnṣe, Ìsẹ́ Àti Ìforúkọsílẹ̀
Ẹgbẹ́ Òṣèlú 'African Democratic Congress' (ADC) ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ìgbìmọ̀ Ìṣàtúnṣe, Ìṣíṣẹ́ àti Ìforúkọsílẹ̀ láti mú ẹgbẹ́ náà gbòòrò káàkiri gbogbo orílẹ̀-èdè.
Alága ẹgbẹ́ òṣèlú náà, Sẹ́nétọ̀ David Mark nígbà tó ń ṣé àgbékalẹ̀…
COAS Ṣé Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú Àwọn Aṣíwájú Ní Ìpínlẹ̀ Niger Láti Dẹ́kun Ìpániláyà
Olórí Ẹgbẹ́ Àwọn Ọmọ-ogun ti mú ìsapá wọn pọ̀ sí i láti mú kí Ìpínlẹ̀ Niger dúró ṣinṣin nípa ṣíṣe ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn Ọba àti àwọn olórí ìbílẹ̀ nínú àtúnyẹ̀wò gbígbòòrò kán lórí ìfiránṣẹ́ àwọn ológun, ìmúlò ìmọ̀ ẹ̀rọ, àti ìmúrasílẹ̀…
Ààrẹ Tinubu Kí Aremu Kú Oríire Ọjọ́ìbí
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti kí Comrade Issa Obalowu Aremu, Olùdarí Àgbà ti 'Michael Imoudu National Institute for Labour Studies (MINILS)', ní ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọdún márùnlélọ́gọ́ta rẹ̀, ó sì yin iṣẹ́ ìsìn rẹ̀ fún ọ̀pọ̀ ọdún sí ìgbòkègbodò…
Olórí Ẹgbẹ́ Ọmọ-ogun Tún Jẹ́rìí sí Ààbò Àwọn Ọmọ-ogun
Olórí Ẹgbẹ́ Ọmọ-ogun, Lt. Gen. Waidi Shaibu, ti tún ṣé ìdánilójú pé ẹgbẹ́ ọmọ-ogun Nàìjíríà yóò máa ṣètìlẹ́yìn fún àwọn olórí àti àwọn ọmọ-ogun pẹ̀lú àwọn ètò ìlera tó yẹ, àwọn ohun èlò ìṣiṣẹ́ àti àtìlẹ́yìn àwọn olórí tó yẹ láti jẹ́ kí wọn…
Ìkọlù Àwọn Agbébọn Sí Ọfiisi Ọgbà Ìtọ́jú Ẹranko Àtijọ́: Makinde Ṣèlérí Òpin Sí Irú Ìkọlù Bẹẹ
Látàrí ìṣẹ̀lẹ̀ ìkọlù àwọn agbébọn sí àwọn òṣìṣẹ́ ọgbà ìtọ́jú ẹranko àtijọ ni Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí àwọn ènìyàn agbègbè náà láti ṣe sùúrù.
Ìṣẹ̀lẹ̀ ìkọlù àwọn agbébọn eléyìí ti Alukoro ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, DSP…
Sarkin Hausawa Ìlú Ìbàdàn Gbésẹ̀: Makinde Kẹ́dùn Pẹ̀lú Olúbàdàn Àti Ẹ̀yà Hausa Ní Ìlú Ìbàdàn
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti fi ikú Sarkin Hausawa ìlú Ìbàdàn, Alahji Ali Dahiru Zungeru we àdánù nla.
Gómìnà, ẹni tó fi olóògbé Zungeru wé olólùfẹ́ àlàáfíà àti adarí tó ṣeé gbẹ́kẹ̀lé náà ló bá Olúbàdàn ilẹ̀ Ìbàdàn,…
Ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Tú Àṣírí Àwọn Oníṣẹ́ Láabi Ni Ìpínlẹ̀ Adamawa.
Ẹgbẹ́ Ọmọ Ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti wọn n pé ni OPHK ti dènà ìwà ìbàjẹ́ ti yóò mú emi opolopo àwọn ènìyàn ló.
Ọwọ́ ba àwọn ènìyàn mẹjọ, ati àwọn odara meji miran ni inu ọjà Gamboru ni èyí tì wọn fẹ gbà Emi ara wọn ati àwọn ènìyàn…