Take a fresh look at your lifestyle.
Adha
Browsing Category

ÌRÒYÌN ORÍLẸ̀-ÈDÈ NÀÍJIRÍÀ

This is a Nigeria news category

Àhésọ ọ̀rọ̀ ni pé àwọn ènìyàn miliọnu méjìlélógún ni kò nílé lórí,ọ̀kẹ́àìmọye…

Minisita fún ètò isẹ́ àti ilé gbígbé lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà,Babatunde Fashola ti àjọ rẹ̀ ti ń fọwọ́sowọ́pọ̀ pèlú minista fún ètọ owó , ìsúná àti ìlànà  láti mú àdínkù bá  ètò ẹ̀yáwó láti dín wàhálà…

Adarí ilé-isẹ́ ológun bèèrè ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn tó ń pèsè ètò ààbò.

Adarí ilé-isẹ́ ológun ti orílẹ̀ èdè Nàìjíríà (COAS), Ogagun Faruk Yahaya ti bèèrè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àjọ eleto ààbò lórílẹ̀-èdè. Ó sọrọ yii lasiko tí ó lọ sí ibi ayẹyẹ ìkẹ́kọ̀ọ́ jáde àwọn  eniyan…

Ẹ fọkàn balẹ̀ kòsí àrùn rọ́mọ lápá-rọ́mọ lẹ́sẹ̀ mọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Àjo tó ń mójútó ìdàgbàsókè ilé-ìwòsàn abọ́dé (NPHCDA) ti sọ pé orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti bọ́ lọwọ aarun rọmọ lapa- rọmọ lẹsẹ. Alásẹ olùdarí NPHCDA, Ọmọwe Faisal Shuaib  ló sọ̀rọ̀ ìdánilójú ọ̀hún nínu…

Ikọ̀ ọmọ ọgun tí wọ́n farapa yóò gba ìtọ́jú tó péye: Adarí ilé-isẹ́ ológun

Adarí ilé-isẹ́ ológun, Ọgagun Faruk Yahaya  ti sọ fún ikọ̀ ọmọ ogun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n farapa pé wọn yóò rí ìtọ́jú tó péye ní ilé ìwòsàn áwọn ọmọ ogun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó wà ní Ìpínlẹ̀…

tí irin bá karin, ọ̀kan á tẹ̀, ikọ̀ ọmọ ogun Nàíjíríà dáńa sun ikọ̀ ọlọ̀tẹ̀, niwọ́n bá…

Ikọ̀ ọmọ ogun àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, ti ọwọ̀  Hadin Kai ti gbánáyá ikọ ọmọ  ọgun ọlọtẹ̀, tí wọ́n sì tún mú ọkùnrin tó ń se agbódegbà fún wọn ní ìlú Katarko tó wà ní ìpínlẹ̀  Yobe , sé tí ikú ilé kò…