Browsing Category
KÓKÓ INÚ ÌRÒYÌN
This is a category for featured story
Malawi Fagilé Owó Ilé-ẹ̀kọ́ Gírámà
Ìjọba Malawi tí kéde pé a tí fagilé owó pàtàkì ní àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gírámà, láti ọjọ́ kìíní oṣù kìíní ọdún 2026, ní ìgbésẹ̀ kan tí a gbé kalẹ̀ láti mú kí ọ̀nà ẹ̀kọ́ gbòòrò sí i jákèjádò Orílẹ̀-èdè.
Ilé-iṣẹ́ Ẹ̀kọ́ jẹ́rìí sí i pé a ti…
Peter Obi darapọ̀ mọ́ ADC fún ìdìbò ọdún 2027
Olùdíje fún ipò Ààre ti ẹgbẹ́ Labour ní ọdún 2023, Ọ̀gbẹ́ni Peter Obi, ti darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ African Democratic Congress (ADC), ẹgbẹ́ òṣèlú ìṣọ̀kan, fún ìdìbò gbogbogbòò 2027.
Obi kede ifi ẹgbẹ rẹ silẹ ni Ọjọọru, ọjọ…
’Super Eagles’ Bẹ̀rẹ̀ Ìgbaradì Fún Ìpele Oníkọ̀ Mẹ́rìndínlógún Tí AFCON 2025
Bí Super Eagles ṣe ń múra sílẹ̀ fún ifẹsẹwọnsẹ wọn nínú ìdíje bọ́ọ̀lù Adúláwọ̀ "African Cup of Nations" (AFCON) ní ìpele oníkọ̀ mẹ́rìndínlógún pẹ̀lú Mozambique ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kìíní, ọdún 2026, àwọn òun márùn-ún wọ̀nyí ló ń ṣẹlẹ̀ sí…
FIFA Ṣàfihàn Orúkọ Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Tí Yóò Jẹ́ Olùdarí Eré Ìdárayá ti 2026
FIFA ti ṣe àkójọpọ̀ Orúkọ Àwọn Ọmọ Nàìjíríà tí yóò jẹ́ Olùdarí eré ìdárayá ní Àgbáyé ti ọdún 2026 ní gbángba, ó sì jẹ́rìí sí i pé àwọn ọgbọ̀n (30) ní a fọwọ́ sí láti dárí àwọn ìdíje àgbáyé ní onírúurú ẹ̀ka.
Àkójọpọ̀ ọdọọdún náà ní…
Àwọn Ọgá Àgbà VON, FRCN Gbóríyìn Fún Zulum Bí Borno Ṣé Ṣàfihàn Àṣà
Àtúnṣe ìrìn-àjò ìgbáfẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Borno gba ìdàgbàsókè ńlá bí Olùdarí Àgbà fún Ilé Akéde Nàìjíríà "Voice of Nigeria (VON)", Malam Jibrin Baba Ndace, àti Olùdarí Àgbà fún Ilé-iṣẹ́ Radio Ìjọba "Federal Radio Corporation of Nigeria (FRCN)",…
Gómìnà Aiyedatiwa Ṣàlékún ààbò jákè jádò Ìpínlẹ̀ Ondo
Gómìnà ìpínlè Ondo, Lucky Aiyedatiwa, ti pàse fún àwon elétò ààbò láti túnbọ̀ lékún ìpààrà lórí ààbò jákè kádò àwọn agbègbè àti agbègbè aginjù látàrí ìkọlù Àgọ́ ọlọ́pàá kan ní ìjọba ìbílẹ̀…
Nàìjíríà kí orílẹ̀ èdè Haiti kú oríire àjọ̀dún ọdún méjìlé-lógún- lénígba…
Mínísítà Nàìjíríà fún ọ̀rọ̀ òkèèrè, Aṣojú Yusuf Tuggar, ti kí Mínísítà fún ọ̀rọ̀ òkèèrè orílẹ̀ èdè Haiti, Jean-Victor Harvel Jean-Baptiste, ìjọba àti àwọn ènìyàn Haiti, kú́ oríire àjọ̀dún òmìnira wọn.…
Póòpù Leo Kẹrìnlá Kéde Láti Gba Àlàáfíà Láyè
Olórí Kátólíìkì, Póòpù Leo Kẹrìnlá, ti ké sí àwọn olórí l'àgbáyé, àwọn ìjọba àti àwọn aráàlú láti gba òun tó pè ní “àlàáfíà aláìlọ́wọ́ àti tí kò ní òun ìjà” gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà tí ó dájú jùlọ sí ìdúróṣinṣin àlàáfíà àgbáyé àti iyì ènìyàn.
…
Gómìnà AbdulRazaq Rọ Àwọn Aráàlú Láti Ṣ’àtìlẹ́yìn Fún-un Bí Ọdún 2026 Ṣé Bẹ̀rẹ̀
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara, Àárín Gbùngbùn Àríwá Nàìjíríà, AbdulRahman AbdulRazaq, ti ké sí àwọn aráàlú láti dúró ṣinṣin nínú àtìlẹ́yìn wọn fún ìṣàkóso rẹ̀ bí ọdún 2026 ṣé bẹ̀rẹ̀.
Ó ṣèlérí pé ìjọba yóò tẹ̀síwájú nínú ìsapá rẹ̀ láti mú…
Ààrẹ Tinubu Yín Hadiza Bala-Usman Ní Ọjọ́ìbí Ọgọ́ta Ọdún
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí gbóríyìn fún Olùdámọ̀ràn Pàtàkì rẹ̀ lórí Ìṣètò Ìlànà àti Olórí Ẹ̀ka Ìpèsè Àpapọ̀ Àárín Gbùngbùn (CRDCU), Hadiza Bala-Usman, fún iṣẹ́ ìjọba tó tayọ̀ nígbà tó ń ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọgọ́ta ọdún rẹ̀.
Nínú…