Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN YÀJÓ-YÀJÓ

This is a category for TRENDING NOW

Agbófinró ìpínlẹ̀ Adamawa, Àwọn Akọ̀ròyìn fọwọ́sowọ́pọ̀ láti túnbọ̀ gbé ètò ààbò ró

Lára ìgbésẹ̀ láti ṣe ìgbélárugẹ ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàrin Agbófinró àti Akọ̀ròyìn, Kọmíṣọ́nà fún Agbófinró, ti ikọ̀ ìpínlẹ̀ Adamawa, CP Dankombo Morris, ti kí aṣojú láti inú ẹgbẹ́ àwọn Akọ̀ròyìn (NUJ), ikọ̀ ti…

Ìpínlẹ̀ Oyo: Àwọn Amòfin gbé ìgbésẹ̀ láti fagilé lílo ẹ̀rọ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ alágbéká…

Ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin ti Ìpínlẹ̀ Oyo ti paá láṣẹ fún ìgbìmọ̀ ètò Ẹ̀kọ́ (Àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti Gíga) láti ṣèjíròrò pẹ̀lú àwọn tó níí ṣe àti láti ṣètò ọ̀nà láti gbé ìfagilé lílo ẹ̀rọ ìbaraẹnisọ̀rọ̀ alágbéká ní…

Ẹgbẹ́ àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ Nàìjíríà lókè òkun yan àwọn aláṣẹ tuntun

Ẹgbẹ́ àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ Nàìjíríà lápapọ̀ lókè òkun ti yan àwọn aláṣẹ tuntun tó pinnu láti jẹ́ aṣojú rere fún Nàìjíríà. Aarẹ ẹgbẹ naa Ọgbẹni Juwon Fayomi, ṣe ipinnu yii nibi ayẹyẹ ifilọlẹ ati Idanilẹkọ fun gbogbogboo…

Ààrẹ Tinubu ṣèdárò ikú ògbóhùntarìgì agbábọ́ọ́lù Nàìjíríà, Christian Chukwu

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti ṣèdárò pẹ̀lú ẹbí, ọ̀rẹ́ àti àwọn alájọṣepọ̀ ògbóhùntarìgì agbábọ́ọ́lù Nàìjíríà Christian Chukwu, tí ó di olóògbé ní ọjọ́ Àbámẹ́ta ní ọmọ ọdún mẹ́rìnlé-láàdọ́rin. Nigba ti o n…
button