Browsing Category
ÌRÒYÌN YÀJÓ-YÀJÓ
This is a category for TRENDING NOW
Igbákejì ààrẹ Bẹ Ìpínlẹ̀ Delta Wò
Igbákejì ààrẹ Kashim Shettima ti gúnlẹ̀ sì ìlú Asaba tii ṣe Olú ìlú ìpínlẹ̀ Delta.
Ìrìn-àjò náà ní ṣe pẹ̀lú Gómìnà ìpínlẹ̀ Delta, Governor Sheriff Oborevwori to dìgbà dẹrulù rẹ̀ lọ si ẹgbẹlẹ́ òṣèlú All Progresses Congress…
CAF Kéde Àwọn igbákejì Ààrẹ tuntun níbi ìpàdé ìgbìmọ̀ Aláṣẹ
Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ (EXCO) fún Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ́lù Láfíríkà (CAF) ti ṣe ìpàdé ní Accra, Ghana, ní ọjọ́ Àbámẹ́ta ṣíwájú ìfigagbága eré bọ́ọ́lù àṣekágbá àwọn ilé ẹ̀kọ́ Agbábọ́ọ́lù Láfíríkà CAF.
Aarẹ…
Igbákejì Adarí ilé pè fún àtìlẹyìn Gúsù ilà oòrùn fún àtúnyàn Ààrẹ Tinubu
Igbákejì Adarí ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú, Ọ̀gbẹ́ni Benjamin Kalu, ti sọ pé sáà kejì tọ́ sí Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí a bá wo àwọn àṣeyọrí tí ó ti ṣe lórí àtúnṣe pàtàkì lórí ọrọ̀ ajé, àjọṣepọ̀ ará ìlú àti…
Mínísítà ṣe ìfilọ́lẹ̀ ilé iṣẹ́ irin Irínwó Mílíọ́nù Dọ́là ní ìpínlẹ̀ Ogun
Mínísítà Nàìjiríà fún ìdàgbàsókè Irin, Ọmọ Ọba Shuaibu Abubakar Audu, ti ṣe àjọyọ̀ ìfilọ́lẹ̀ gbangba ti ilé iṣẹ́ irin Inner Galaxy Group’s Stellar, idokowo Irínwó Mílíọ́nù Dọ́là ní ìpínlẹ̀ Ogun ní Gúsù Iwọ̀…
Abia 2027: Àwọn Adarí agbègbè rọ igbákejì adarí ilé láti díje Gómìnà
Àwọn agbaagba Ukwa-Ngwa ní gbègbè Aba ìgbà kan rí ní ìpínlẹ̀ Abia Abia ti bẹ igbákejì adarí ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin, Ọlọla Benjamin Okezie Kalu, láti díje fún ipò Gómínà nínú ìbò gbogbogbòò ọdún 2027.
Awọn…
Ààrẹ Tinubu kí adarí Itsekiri kú àádọ́ta ọdún
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti kí Ayirimi Emami, ẹni tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn adarí Itsekiri, oníṣòwò, àti olùṣàánú, fún àjọyọ̀ àádọ́ta ọdún rẹ̀.
Ninu alaye kan lati ile iṣẹ Aarẹ, Aarẹ gboriyin fun Emami fun awọn ipa…
Ìpínlẹ̀ Enugu Gbá Imọlẹ̀ Ìṣọ̀kan Ìdárayá Tí Orílẹ̀-èdè
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Enugu, Peter Mbah, tí gbá imọlẹ̀ ìṣọ̀kan tí èrè ìdárayá àpapọ̀ (National Sports Festival), l'àkókò tó ṣé ìlérí ìkópa kíkún tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tí ìpínlẹ̀ rẹ̀ nínú èyí tó mbọ, tí yóò wáyé ní Ìpínlẹ̀ Ogun, Nàìjíríà.
Mbah,…
Adarí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Tinubu padà wálé ní ọjọ́ Ajé
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu yóò padà sí Nàìjíríà ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kọkàlé-lógún, oṣù kẹrin lẹ́yìn àbẹ̀wò iṣẹ́ sí Yúróópù.
Agbẹnusọ Aarẹ, Bayo Onanuga, ni o kede rẹ wẹrẹ lori ayelujara X, bayii pe “Aarẹ Bola Tinubu…
Ààrẹ Tinubu ṣèdárò ikú Pope Francis
Ààrẹ Bola Tinubu ti ṣe ìdárò lẹ́yìn ikú ẹni ọ̀wọ̀, Pope Francis, tí ó sì ṣàpéjúwe rẹ̀ bíi ‘onítẹríba ẹrú ọlọ́run’ àti ‘Agbẹnusọ fún òdodo, àlàáfíà, àti fún aláìní ’.
Ninu alaye kan ti wọn fisita fun gbogbo…
Àjíǹde: Adarí ilé, Igbákejì rọ àwọn kírísítíẹ́nì láti kọ́ ìṣe kŕisítì
Adarí ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú, ọ̀gbẹ́ni Abbas Tajudeen àti igbákejì rẹ̀ Benjamin Kalu ti rọ àwọn ọmọ lẹ́yìn kírísítí láti kọ́ ìṣe ìfaradà Jésù Kírísítì.
Wọn rọ awọn ọmọ Naijiria lati ni ifẹ ara wọn lai bikita ẹya, ẹsin,…