Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN YÀJÓ-YÀJÓ

This is a category for TRENDING NOW

NELFUND pín iye owó tó lé ní Bílíọ́nù mẹ́rìndínlọ́gọ́ta Náírà fún ẹ̀yáwó akẹ́kọ̀ọ́

Àjọ tí ń rísí owó yíyá fún ẹ̀kọ́ ní Nàìjíríà (NELFUND), ti kéde pínpín iye owó tó lé ní Bílíọ́nù mẹ́rìndínlọ́gọ́ta Náírà láìgba èlé fún àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga tíjọba jákèjádò orílẹ̀-èdè láti bí…

NGO ní òun ti ní ipa lórí àwọn ènìyàn méjìlé-lọ́gbọ̀n Mílíọ́nù ní abala ìtọ́jú…

Ilé iṣẹ́ tí kìí ṣe tìjọba kan, Nigeria Solidarity Support Fund, NSSF, ti sọ pé òun ti ní ipa lórí àwọn ènìyàn méjìlé-lọ́gbọ̀n Mílíọ́nù ní ọdún mẹ́rin tí òun ti ń ṣiṣẹ́ ní abala ìtọ́jú ìlera lórílẹ̀-èdè.…

Hajj 2025: Kwara gbé àwọn arìnrìn àjò mímọ́ ikọ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹta ti ẹdẹ̀ẹ́gbẹ̀ta-ó-lé-ọgọ́ta Lọ…

Ikọ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹta àwọn arìnrìn àjò mímọ́ tí ó tó ẹdẹ̀ẹ́gbẹ̀ta -ó -lé -ọgọ́ta láti ìpínlẹ̀ Kwara gbéra lọ sí Saudu Arabia ní ọjọ́ Àbámẹ́ta láti ṣe iṣẹ́ mímọ́, tí ó sì jẹ́ pé ọkọ̀ òfurufú Max ni ó gbé wọn láti…

Ààrẹ Tinubu túnbọ̀ fìdí ìpinnu rẹ̀ múlẹ̀ lóri ìfọ̀rọ̀jomitoro ọ̀rọ̀ láàrin ẹlẹ́sìn,…

Adarí Nàìjíríà, Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti túnbọ̀ fìdí ìpinnu rẹ̀ múlẹ̀ lóri ìṣàgbélárugẹ àjọṣepọ̀ ìfọ̀rọ̀jomitoro ọ̀rọ̀ láàrin Àwọn ẹlẹ́sìn, ìgbàmọ́ra, àti ìfọwọ́sowọ́pọ̀ jákèjádò lágbàáyé Ààrẹ naa…

Ètò Ìkànìyàn Ṣe Pàtàkì Fún Ìgbáradì Ọjọ́ Iwájú Nàìjíríà – Ààrẹ Sẹ́nètì

Ààrẹ àwọn Senetọ̀ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Sẹ́nétọ̀ Godswill Akpabio ti sọ pé ó pan dandan láti ṣe ètò Ìkànìyàn láti lè jẹ́kí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pèsè fún ọjọ́ ọlá èniyàn rẹ. Sẹ́nétọ̀ Akpabio sọ pé ó ye kí ètò ìkànìyàn náà ti wáyé…

Mínísítà gbóríyìn fún Ààrẹ bí ó se ka àwọn iṣẹ́ àkànṣe tí yóò ṣíṣọ lójú rẹ̀…

Mínísítà Nàìjíríà fún olú ìlú (FCT), Ọ̀gbẹ́ni Nyesom Wike, ti ṣàlàyé pé Abuja ti rí àyípadà tó lápẹẹrẹ lábẹ́ ìṣàkóso Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu. Mínísítà sọ eyi di mimọ lasiko abẹwo ibojuto iṣe Akanṣe opopona…
button