Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN YÀJÓ-YÀJÓ

This is a category for TRENDING NOW

Kọmíṣọ́nà fún ètò ìlera Anambra pinnu ìtọ́jú alábọ́ọ́dè, tósì tún múná dóko

Kọmíṣọ́nà fún ètò ìlera ní ìpínlẹ̀ Anambra, Dokita Afam Obidike, túnbọ̀ fìdí ìpinnu ìjọba ìpínlẹ̀ múlẹ̀ lórí ìpèsè ètò ìtọ́jú tó wà lárọwọ́tó, tí owó rẹ̀ kò sì tún ní jara lọ fún àwọn ará ìlú níbi…

Àwọn alájọṣepọ̀ ààrẹ Benin fi ẹ̀wọ̀n ogún ọdún gbára lórí ìgbèrò ìfipá gbàjọba

Àwọn arákùnrin méjì kan tí wọ́n súnmọ́ ààrẹ orílẹ̀ - èdè Benin, ti fi ẹ̀wọ̀n ogún ọdún gbára lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n mú wọn lọ́dún tó kọjá lórí ìgbèrò ìfipá gbàjọba lórílẹ̀ èdè náà. Ile Ẹjọ ti n risi ẹṣẹ…

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Kẹ́dùn Ikú Ẹ̀gbọ́n Rẹ̀, Onímọ̀ Ẹ̀rọ Sunday Makinde

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Seyi Makinde ti kẹ́dùn ikú ẹ̀gbọ́n rẹ̀, Onímọ̀ Ẹ̀rọ Sunday Makinde. Àtẹ̀jade ti Oludamọran fún Gómìnà lórí ìròyìn, Suleimon Olanrewaju fi síta fún àwọn oníròyìn ní ìlú Ìbàdàn tíì ṣe Olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ni Ẹkùn…

Gómìnà Kwara pàdánù Ọ̀gá Àgbà fún àwọn òṣìṣẹ́ AbdulKadir Mahe

 Ọ̀gá Àgbà fún àwọn òṣìṣẹ́ (CoS) fún Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara, Ọmọọba AbdulKadir Mahe, ti jẹ́pè olúwa. Ó jẹ́pè olúwa ní àárọ kùtù ọjọ́ Àbámẹ́ta. Ọ̀gá àgbà Akọ̀wé sí Gómìnà, Mallam Rafiu Ajakaye, ní ó kéde…

Igbákejì Ààrẹ Shettima kẹ́dùn pẹ̀lú Gómìnà Ìpínlẹ̀ Jigawa lórí Àjálù méjì tó…

Ààrẹ Bọla Tinubu ti yan àwọn asojú kan tí Igbákejì Ààrẹ Kashim Shettima ṣadarí, láti ṣe àbẹ̀wò ìkẹ́dùn sí Gómìnà àti àwọn ènìyàn Jigawa lórí ikú ìyá àti ọmọkùnrin  Gómìnà ìpínlẹ̀ náà, Alhaji Umar…
button