Browsing Category
ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GBÌN
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kaduna Gba Akẹgbẹ́ Rẹ̀ Nímọ̀ràn Láti Lo Ànfààní Ètò Ọ̀gbìn Fún…
Gómìnà ìpínlẹ̀ Kaduna ti gba àwọn akẹgbẹ́ rẹ ní ìmọ̀ràn láti lo ànfààní ètò ọ̀gbìn fún ìgbélárugẹ ọrọ̀ ajé àti mímú ọ̀tọ̀ǹkùlú ènìyàn jáde kúrò nínú ìsẹ́.
Ó fi ìmọ̀ràn náà léde níbi àjọ…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kaduna Dá Ilé Iṣẹ́ Ìṣelọ́jọ̀ Àti Ìkórè Ohun Ọ̀gbìn Sílẹ̀
Lójúnà àti dènà sísòfò nǹkan oko fún àwọn àgbẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Kaduna, ìjọba ìpínlẹ̀ náà, lábẹ́ẹ Kaduna State Agro- Enhancement and Livelihood Impovement Support (APPEALS) ti setán láti dá ilé isẹ́ mẹ́ẹ̀dógún sílẹ̀…
Ìpínlẹ̀ Ògùn ṣe ìfilọ́lẹ̀ ètò ìdàgbàsókè ọ̀pọ̀lọpọ̀ mílíọ́nù Dọ́là SAPZ
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ògùn ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìdàgbàsókè ètò iṣé àdàṣe pàtàkì ilé-iṣẹ́ ìpèsè àti iṣẹ́- ọ̀gbìn Ìlú oní ọ̀pọ̀lọpọ̀ mílíọ́nù Dọ́là (SAPZ),gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan nínú àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́jọ tí wọ́n mú fún…
Kò Ní Sí Ọ̀wọ́ngógó Oúnjẹ Ní Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà Lọ́jọ́ Iwájú
Mínísítà ètò ọ̀gbìn àti ìdàgbàsókè ìgbèríko, ọ̀mọ̀wé Muhammewd Abubakar ti fi dá gbogbo ọmọ Nàìjíríà lójú pé kò ní sí ọ̀wọ́ngógó oúnjẹ ní ọjọ́ iwájú.
Abubakar fi àrídájú náà léde…
Kíkó Oúnjẹ Jáde Lọ́nà Àlùmọ̀kọ́rọ́yí Ti Di Èèwọ̀ Ní Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà
Ìjọba àpapọ̀ ti ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn tí ọ̀rọ̀ kàn láti pinwọ́ kíkó oúnjẹ jáde lọ́nà àìtọ́ lọ sí orílẹ̀ èdè míràn.
Mínísítà ètò ọ̀gbìn àti ìdàgbàsókè ìgbèríko, ọ̀mọ̀wé Mohammed Abubakar fi…
Àdéhùn Láàrín Russia Àti Àjọ Àgbáyé (UN) Lórí Ọjà Òkèèrè
Russia tí fí ìwé ẹdun ọkàn nípa ìwé ìṣẹ́ àdéhùn ọjà òkèèrè tí Black Sea Grain sí Àjọ Àgbáyé (United Nations).
Gennady Gatilov, aṣojú Russia sí United Nations, sọ pé “Ta bá ríi pé kò sí àtúnṣe sí ìwé àdéhùn náà, lórí ètò àwọn ọkà ati…
Ìjọba Nàìjíríà Wá Ojútùú Sí Ìsòro Ọ̀wọ́n Oúnjẹ
Ní àyájọ́ oúnjẹ ti ọdún 2022, ìjọba àpapọ̀ ti pè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láti wá ọ̀nà àbáyọ sí ìsòro ọ̀wọ́n oúnjẹ bí wàhálà náà se wà jákèjádò gbogbo àgbáyé.
Mínísítà tí ó wà fún ètò…
Ilé-iṣẹ́ Ajílè ọ̀gbìn Dangote ṣe Ìgbéláruge Ìdàgbàsókè iṣẹ́-ọ̀gbìn – Ẹgbẹ́
Ilé-iṣẹ́ ajílè Dangote,gẹ́gẹ́ bí nǹkan tí Ọ̀gbẹ́ni Olúṣọlá Obadimú, Olùdarí Gbogbogboò Ẹgbẹ́ Aṣojú Àwọn Ilé-iṣẹ́ Ìṣòwò, Ilé-iṣẹ́ tó ń ṣẹ̀dá,àlùmọ́nì inú ilẹ̀, àti iṣẹ́-ọ̀gbìn (NACCIMA), yóò ṣe ìgbéláruge…
Ẹka Ìjọba Ìpínlẹ̀ Anambra Ti Gbé Ìgbésẹ̀ Láti Tán Ìsòro Tí Ó Ń Kojú Àyíká.
Ẹka tí ó ń mójú tó àyíká àti àyípadà ojú ọjọ́ ti pè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn lẹ́gbẹ́-lẹ́gbẹ́ ní ìpínlẹ̀ náà lójúnà àti gbógun ti àwọn ìsòro tí ó ń kojú àyíká wa.
Ìjọba tí ó wà lóde ní…
Àjọ Tó Ń Sọ Nípa Bójú Ọjó Se Rí Ti Rọ Àwọn Àgbẹ̀ Orílè-èdè Yìí Láti Ka Ìwòye Ọ̀rọ̀ Ojú Ọjọ́ Sí
Àjọ to ń sọ nípa bóju Ọjó se rí (NiMET) ti Orílè-èdè yìí ti sọ pé bí àwọn àgbẹ̀ ṣe ń pàdánù ọ̀pọ̀ irè oko lórílẹ̀ èdè yìí kò sẹ̀yìn àìka ọ̀rọ̀ àjọ náà tó sọ̀rọ̀ nípa bójú ọjó se rí sí.
Adarí ẹ̀ka ti ojú ọjọ́ NiMET , Ògbẹ́ni Adélékè…