Browsing Category
ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GBÌN
Ilé iṣé (NDE) Ṣe Ìdánilékọ̀ọ́ Fún Àwọn Ènìyàn Àádọ́ta Ní Ìpínlẹ̀ Delta Nípa Ohun Ọ̀gbìn.
Ilé iṣé NDE ni ìpínlẹ̀ Delta tí ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún Àwọn ènìyàn àádọ́ta ni ìpínlẹ̀ náà fún ìmọ̀ tó péye lórí ìdàgbàsókè ohun ọ̀gbìn.
Àgbékalẹ̀ ètò dì mímọ̀ láti ẹnu Adarí àgbà fún àjọ náà, Mallam Abubakar Nuhu Fikpo, o ní ìdánilékọ̀ọ́…
Ẹgbẹ́ Pè Fún Àwọn Onímọ̀ Láti Ṣàkoso Ètò Ọ̀gbìn.
Ẹgbẹ́ àwọn àgbẹ̀ tí pè Ààrẹ Bola Tinubu láti yan ẹni tó ní ìmọ̀ nípa ètò ọ̀gbìn láti lè ma ṣe àkóso rè fún ìdàgbàsókè lórí ọ̀rọ̀ ètò ọ̀gbìn
Àwọn ọjọgbọn to lè ní ààdọ́rin tó n ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn ohun tó wúlò jùlọ nínú ètò ọ̀gbìn, ni o pé…
Àkókò Ilẹ̀ Tútù: Àwọn Àgbẹ̀ Ìpínlẹ̀ Gombe Bèrè Fún Àtìlẹ́yìn Lórí Omí Yalé Tó Ṣẹlẹ̀ Lọ́dún 2022.
Àwọn àgbẹ̀ kánkan ni ìpínlẹ̀ Gombe ti ìṣẹ̀lẹ̀ Àgbàrá òjò kò gbogbo ohun oko wọn lọ lọ́dún tó kọjá ti bẹ ìjọba láti ṣe ìrànlọ́wọ́ fún wọn ní ọdún yìí kí ànfààní ba lè yọ láti ṣiṣẹ́ oko.
Àwọn àgbẹ̀ sọ ọ̀rọ̀ yìí jáde nígbà tí wọn ń bá àwọn…
Ó Ṣe Pàtàkì Làti Ní Ìgbẹkẹ̀lé Nínú Àwọn Àgbẹ̀ Fún Ààbò Tó Péye Lórí Ètò Oúnjẹ.
Àgbẹ̀ akọ́ṣẹ́mọsẹ́, ti orúkọ rẹ n jẹ Ìyáàfin Tolulope Aina, ti rọ àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú àwọn àgbẹ̀ àti láti ṣe àtìlẹ́yìn fún wọn láti mójú tó ètò ọrọ̀ ajé àti ààbò tó péye fún ètò ounjẹ ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.…
Àjọ (NDE) Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Owó Fún Awọn Akópa Pẹ̀lú Àjọ (AES) Ni Ìpínlẹ̀ Ogun.
Láti dènà kò sí iṣẹ́ lọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn àti láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ounjẹ àjọ (NDE)yà awọn ènìyàn ní owó to kópa pẹ̀lú ilé ìṣẹ́ òhun ọ̀gbìn (AES)ni ìpínlẹ̀ ogun ni owó.
Níbi ayẹyẹ náà to waye ni ààfin ọba ni Ilaro, adarí fún àjọ…
Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣe Ìdánilékọ̀ọ́ Fún Àwọn Àgbẹ̀ Ìpínlẹ̀ River.
Bí a ṣe wọ inú àkókò òjò ló ni ilé iṣé ìjọba fún Ohun Ọ̀gbìn àti ìdàgbàsókè agbègbè (FMARD) rọ àwọn àgbẹ̀ ni agbègbè River láti dènà omí yalé ti o le wáyé.
Wọn ní láti dènà èyí tó ṣẹlẹ̀ ni ọdún tó kọjá, ìdí èyí ni ìjọba ṣẹ ìdánilékọ̀ọ́…
Ilé iṣé (MOK) Pèsè Okò Ohun Ọ̀gbin Fún Àwọn Àgbẹ̀ Ni Ìpínlẹ̀ Kwara.
Ilé iṣé Okunlola Kayode Foundation (MOK) to jẹ ilé iṣé alàádáni ní ìjọba ìbílẹ̀ offa ni Ìpínlẹ̀ Kwara ti pèse ọkọ̀ nkán ọ̀gbìn fún àwọn àgbẹ̀ lati ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ètò ọ̀gbìn.
Ilé iṣé náà ló sọ èyí di mímọ̀ nínú ìpàdé pẹlu àwọn ẹgbẹ́…
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Cross River Yóò Mú Ìdàgbàsókè Bá Ètò Nkán Ọ̀gbìn.
Gómìnà ìpínlẹ̀ Cross River Bassey Otu tí sọ èròngbà rẹ láti mú ìdàgbàsókè bá ẹ̀tọ̀ nkán ọgbin, nípa mí mójú tó abala mẹ́ta nínú ètò ọgbin, abala epo pupa, abala ẹja àti abala kòkó.
Gómìnà sọ èyí níbi ọ̀rọ̀ àkọ́kọ́ bí Gómìnà to waye ni…
Mínísítà Fún Ìpínlẹ̀ Ogun Rọ Àwọn Ọ̀dọ́ Láti Kópa Nínú Iṣé Èja SínSìn.
Mínísítà fún ìdàgbàsókè ni Ìpínlẹ̀ Ogun, ìyáàfin Kikelomo Longe, ti gbà àwọn Ọ̀dọ́ ni mọ̀ràn láti lò àǹfààní to wa nínú ọ̀sìn ẹja ní iṣé lọ́wọ́.
Ìyáàfin Longe sọ èyí níbi ayẹyẹ ìpàdé ọlọ́sẹ̀ mẹ̀ta nípa ọ̀sìn ẹja ni ìlú Abeokuta.…
Ìpínlẹ̀ Bauchi bẹ̀rẹ̀ tit́a ajílẹ̀ fún àsìkò òjò ọdún 2023
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Bauchi, ní ọjọ Iṣẹgun, bẹ̀rẹ̀ tit́a ajílẹ̀ fún àsìkò ọ̀gbìn 2023,ní iye owó ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dógún Náírà fún àpò kan.
Gómìnà Bala Mohammed sọ eléyìí níbi ìfilọ́lẹ̀ Àsìkò Ọ̀gbìn 2023 ati Títa…