Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÈTÒ Ọ̀GBÌN

Gómìnà ìpínlẹ̀ Sòkòtò Tẹnumọ́ Ìdí Tí o Fí Ye ki Wọn Da Àgbè Tó Dágájírá Mọ.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Sòkòtò, Ọgbẹni Ahmad Aliyu tẹnumọ́ anfààní to wa nínú ki ènìyàn ní àgbè tó Dágájírá láti se ètò ohun ọ̀gbin pẹ̀lú ìmọ̀ láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ọ̀gbìn. Ó sọ èyí di mímọ nígbà tí o ṣe àbẹ̀wò sí ilé iṣé ìjọba fún ètò ọ̀gbìn…

Gómìnà ìpínlẹ̀ Sòkòtò Tẹnumọ́ Ìdí Pàtàkì Tí o Ye ki Wọn Da Àgbè Tó Dágájírá Mọ.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Sòkòtò, Ọgbẹni Ahmad Aliyu tẹnumọ́ anfààní to wa nínú ki ènìyàn ní àgbè tó Dágájírá láti se ètò ohun ọ̀gbin pẹ̀lú ìmọ̀ láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ọ̀gbìn. Ó sọ èyí di mímọ nígbà tí o ṣe àbẹ̀wò sí ilé iṣé ìjọba fún ètò ọ̀gbìn…

Àwọn Onímọ̀ Nípa Ètò Ọ̀gbìn Yóò Rí Dájú Wí Pé Ìdàgbàsókè Bá Ètò Ọ̀gbìn – Ọ̀gá Àgbà ARCN

Ilé iṣé Ìwádìí nípa ọ̀gbìnni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ARCN sọ wí pé àwọn yóò sá gbogbo ipa àwọn láti rí wí pé ètò ògbìn ni ilọsiwaju pẹ̀lú ìbámu labẹ ijoba lati ní anito oúnjẹ ni ilé. Akọ̀wé fun ẹgbẹ́ ARCN Garba Sharubutu ni o sọ èyí di mímọ…

Àwọn Tí Ó Ń Fi Owó Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Ènìyàn Ṣe Ìrànlọ́wọ́ Fún Àwọn Àgbè Ni Ìpínlẹ̀ Enugu.

Ọgá àgbà pátápátá fún ilẹ iṣé Paschal -Rico, Olóyè Pascal Aneke àti Ọ̀gbẹni Sunday Ozokolo láti Orílẹ̀-èdè Switzerland ni ọjọ́ ìsinmi Pin àwọn ohùn èlò ìrànlọ́wọ́ fún àwọn àgbẹ̀ ìgbèríko ni ìjọba ìbílẹ̀ Ezeagu ni Ìpínlẹ̀ Enugu. Àwọn…
button