Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌLERA
This is a category for health news
Àjọ UNICEF Pèsè Mílíọ̀nù Mẹ́ẹ̀dógún Owó Ìrànwọ́ Fún Ìpínlẹ̀ Kaduna,Kebbi Àti Bauchi
Àjọ UNICEF ti pèsè Mílíọ̀nù Mẹ́ẹ̀dógún Owó Ìrànwọ́ fún Ipinlẹ Kaduna,Kebbi, àti Bauchi ní ọnà láti ró ijọba àti agbègbè lágbára fún ìpèsè ohun ètò tó jẹ mọ́ ìbálòpọ̀, ètọ́ ọmọnìyàn àti ohun ètò ìlera.
Nígbàtí ó ń sọ̀rọ̀ níbi ètò Ọlọ́jọ́…
Ìpínlẹ̀ Kwara Se Ètò Ìpolongo Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Fún Àwọn Ògo Wẹẹrẹ
Ìpínlẹ̀ Kwara ti gbáradì láti se ètò àjẹsára fún àwọn ògo wẹẹrẹ mílíọ̀nù kan tí wọn kò ju ọmọ ọdún márùn-ún lọ ní èyí tí ìrètí wà pé yóò wáyé ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n sí ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n osù…
Ìgbésẹ̀ Wáyé láti Se Ètò Mọ̀ọ́kọ-mọ̀ọ́kà, Iṣẹ́ Ọwọ́ Fún Àwọn Tí Ó Ní Ìpèníjà Ara…
Àjọ Ọmọ lẹ́yìn Kírísítì kan pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn ènìyàn àgbègbè Taimako ti se ìfilọ́lẹ̀ àkànṣe iṣẹ́ kan èyí ti ó ní àfojúsùn ìdàgbàsókè ètò ẹ̀kọ́ àti iṣẹ́ ọwọ́ fún àwọn tí ó ní ìpèníjà ara ní…
Gombe: Agbófinró bẹ̀rẹ̀ ètò ìwòsàn ọ̀fẹ́
Lára àwọn ètò láti ṣàmì ayẹyẹ Àyájọ́ Àkọ́kọ́ irú ẹ̀ ti Agbófinró ní ìpínlẹ̀ Gombe, Adarí Agbófinró ti pèsè ètò ìwòsàn ọ̀fẹ́ láti ṣàtúnṣe lórí ìlera àwọn ará ìlú àti láti túnbọ̀ fìdí àjọṣepọ̀…
Ìpínlẹ̀ Taraba: Obìnrin Àkọ́kọ́ Yóò Ṣe Àgbékalẹ̀ Ilé Ìwòsàn Alágbèéká
Obìnrin àkọkọ, Sẹ́nétọ̀ Oluremi Tinubu ti ṣe ileri láti fún ìjọba ìpínlẹ̀ Taraba ní Ilé Ìwòsàn Alágbèéká látàrí ètò ìjọ̀ba-ìrètí ọtun, Renewed Hope Initiative, RHI.
Ó sọ eyi ní Jalingo níbi ìfilọ́lẹ̀ Ilé Ìwòsàn Alágbèéká àti ètò ẹ̀kọ́…
Ìfètòsọ́mọbíbí Gbalé-gboko Ní Ìpínlẹ̀ Yobe
Àjọ tí ó ń polongo ìfètòsọ́mọbíbí ní Ìpínlẹ̀ Yobe sàfihàn ìdùnnú gẹ́gẹ́ bí àwọn obìnrin Ìpínlẹ̀ Yobe se gbà lọ́pọ̀ yanturu láti se ètò ìfètòsọ́mọbíbí
Alága Àjọ náà, Mustapha Musa ni ó sọ ọ̀rọ̀…
Nọ́ọ̀sì Se Àyẹ̀wò Ọ̀fẹ́ Fún Àwọn Ènìyaln Ìlú Kaduna
Onímọ̀ ìṣègùn Òyìnbó, Nọ́ọ̀sì Deborah Abeku Vaku ti se àyẹ̀wò ọ̀fẹ́ fún àwọn ènìyàn àádọ́jọ ní Ìpínlẹ̀ Kaduna
Lásìkò àyẹ́wó náà èyí tí ó wáyé ní Narayi, Ìpínlẹ̀ Kaduna, ó pín àwọn Ohun èlò…
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Abia Se Ìfilọ́lẹ̀ Ìlànà Ìlera Fún Àwọn Òsìṣẹ́ Ìjọba
Gómìnà Alex Otti ti Ìpínlẹ̀ Abia, ní Ọjọ́bọ̀ se ìfilọ́lẹ̀ ìlera ìdáàbò bò ẹ̀mí èyí tí ó ní àfojúsùn láti pèse ìlera fún àwọn òsìṣẹ́ ìjọba ní owó péréte
Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ níbi ètò náà ní…
Àjọ Aláàánú Ọmọnìyàn Ti Ọbasanjọ Pín Ohun Èlò Ìlera Ní Gúsù Ìlà Oòrùn
Àjọ Aláalánú Ọmọnìyàn, ti Olusẹgun Ọbasanjo , ní Ọjọ́bọ̀, bẹ̀rẹ̀ pínpín ohun èlò ìlera fún àwọn tí ó ní ìpèníjà gbígbọ́ ọ̀rọ̀ jákè-jádò Gúsù Ìlà Oòrùn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà
Àjọ Olusẹgun…
Ẹ Ri Wí Pé Ẹ Mọ Iṣé Yìí Dájú: Mínísítà Fún Ètò Ìlera.
Mínísítà fún ètò ìlera fun ìpínlẹ̀ Dọ́kítà Salako ti rọ àwọn òṣìṣẹ́ ìlera láti rí wí pé wọn mọ iṣé wọn de ojú ààmì o sí da wọn lójú.
Salako sọ èyí di mímọ̀ ni ìlú Abuja níbi, ayẹyẹ ibura fún àwọn òṣìṣẹ́ agbègbè àwọn ènìyàn…