Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÁNILÁRAYÁ
This is a category for entertainment news
Kalu Ikeagwu Gba Àmì Ẹ̀yẹ Ẹni Tí Ó Mọ Eré Se Jùlọ Ti Ilẹ̀ Áfíríkà, Ọdún 2023
Gbajú-gbajà eléré fíìmù ọmọ Orilẹ-ede Naijiria ti jáwé olúborí tí ó sì gba àmì ẹ̀yẹ níbi ayẹyẹ fún àwọn olùkópa nínú fíìmù Áfíríkà lati ara ipa ribiribi ti o ko ninu eré Ugandan Kan ti a mọ si “Kafacoh”.…
Olùwá-oúnjẹ India Kí Olùwá-oúnjẹ Nàìjíríà, Hilda Baci Kú Oríire
Olùwa-oúnjẹ India, Lata Tondon ti kí Olùwa-oúnjẹ Nàìjíríà, Hilda Effiong Bassey, tí wọ́n mọ̀ sí Hilda Baci, ku oríire lẹ́yìn tí ó ti fi àjùlọ hàn. Ó fi ìtàn balẹ̀ bí Olùwá-oúnjẹ tó yára, tó pẹ́ jùlọ ní àgbáyé.
Hilda Baci ti kọ orúkọ rẹ̀…
Kíkun Nǹkan Fún Ọjọ́ Mẹ́ta: Ọ̀dọ́mọbìrin Kan Gba Òúntẹ̀ Àjọ Àgbáyé Láti Tẹ̀ Síwájú
Ọ̀dọ́mọbìrin ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó máa ń kun nǹkan, Oyinlola ti wà ní bèbè àseyege ti ìwé ìrántí Guinness gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó leè kun nǹkan pẹ́ jù ní àgbáyé.
Ẹni tí ó se dáradára jù nínú ìdíje náà ní àtijọ́, Ronald…
Aláwàdà Kẹrí-kẹrì Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Se Ayẹyẹ Ọdún Kẹẹ̀wá Lẹ́nu Iṣẹ́
Adẹ́rìn-ín Pòṣónú Ọmọ Orilẹ-ede Naijiria, Emeka Erem ti gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ajebo ni ó ti gbáradì láti se ayẹye ọdún kẹẹ̀wá ti o ti n ba iṣẹ́ náà bọ̀.
Olùdánilárayá naa salaye pe yoo seré fun awọn…
Davido Tún Se Bẹbẹ Nínú Orin
Oǹkọrin tàkasùfé Afrobeat, David Adeleke, ti gbogbo ènìyàn mọ̀ ṣí "Davido" tún ṣe bebe lẹ́ka orin rẹ̀ tó pè àkọ́lé rẹ̀ ní "Timeless".
Èyí wáyé lẹ́yìn tí wọ́n kéde rẹ̀ pé ó se dáradára nínú àtẹ orin pé ó jẹ́ olùkọrin àkọ́koọ́ nínú Àádọta…
Akọrin Ọmọ Nàìjíríà, Tèmíladé Ọpẹ́níyì, Gba Àmì Ẹ̀yẹ Orin
Akọrin Ọmọ Orílẹ̀-èdè Naijiria, Tèmíladé Ọpẹ́níyì, ti gba ami ẹ̀yẹ Orin tí wọ́n ń pè ní "Grammy award."
Tem's gba àmì ẹ̀yẹ-Melodica Rap Performance tí ó dára jù ní ọjọ́ kẹfà osù Kejì ọdún 2023.
Ó gba àmì…
Àwọn Akọ́ṣẹ́-mọṣẹ́ Oníròyìn Gbé Ìgbéṣẹ̀ Tako Ìròyìn Òfegé Lórí Ẹ̀rọ Ayélujára
Àjọ akọ́ṣẹ́-mọsẹ́ Oníròyìn àgbáyé pẹ̀lú ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn olùkópa lórí ìfìròyìnléde ti gbé ìgbésẹ̀ akin lójúnà àti gbógun ti ìtànkálẹ̀ ìròyìn òfegé lórí ẹ̀rọ ayélujára.
Nínú àpérò…
Àkọrín Ọmọ Nàìjíríà Ayra Starr Tí Wọ́gilé Ìrìn-àjò Rẹ̀ Sílẹ Òkèèrè Látàrí Ètò Ìwé Ìrìn-àjò
Ogbontarigi àkọrín Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ayra Starr tó ń kọ́rín káàkiri àgbáyé lọ́wọ́lọ́wọ́ tí wọ́gílé ìrìn-àjò látí lọ́ sí Berlin, Bergenfest, ati Copenhagen lórí òfin ètò ìwé ìrìn-àjò àwọn Orílẹ̀-èdè wọnyí.
O ṣé ìkéde yìí lórí…
Aláwàdà Kẹríkẹrì Ọmọ Nàìjíríà Pinnu Láti Wà Lókè Téńté Ní Gbogbo Ìgbà Nínú…
Gbajú-gbajà adẹ́rìn-ín-pòsónú, Samuel Animasahun ti gbogbo aye mọ si Broda Shaggi ti pinnu láti má fi ipò apanilẹ́rìn-ín t́i ó peregedé jùlọ, èyí tí ó ti gbà, sílẹ̀ fún ẹni kẹ́ni.
Nígbà ti o n gba àmì ẹ̀yẹ naa,…
Seun Kuti Fi Oyè Tí Ó Gbà Lẹ́wọ̀n Sí Orí Ẹ̀rọ Ayélujára
Gbajú-gbajà olórin tí ó tún jẹ́ ọmọkùnrin tí ó kéré jùlọ fun Fela Anikulapo, Seun Kuti ni o ti fi oyè ti o gba nigba ti o wa ni àhámọ́ ọgbà ẹ̀wọ̀n Panti léde ni ori ẹrọ ayelujara rẹ.
Eléyìí waye lẹ́yìn ọjọ…