Take a fresh look at your lifestyle.

Davido Tún Se Bẹbẹ Nínú Orin

0 151

Oǹkọrin tàkasùfé Afrobeat, David Adeleke, ti gbogbo ènìyàn mọ̀ ṣí “Davido” tún ṣe bebe lẹ́ka orin rẹ̀ tó pè àkọ́lé rẹ̀ ní “Timeless“.

Èyí wáyé lẹ́yìn tí wọ́n kéde rẹ̀ pé ó se dáradára nínú àtẹ orin pé ó jẹ́ olùkọrin àkọ́koọ́ nínú Àádọta Olórin tó lo ọ̀sẹ̀ méjì lori àtẹ ni sísẹ̀ntẹ̀lé lórí orin bí wọ́n se tẹ̀wọ̀n sí nínú ti àtẹ orin tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Davido sì fèsì lórí ẹ̀rọ ayélujára twitter rẹ̀ fún àṣeyọrí aláìlẹ́gbẹ́ náà.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.