Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ

This is a category for business news

Ìròyìn Ayọ̀: Ìrètí Wà Pé Ọ̀wọ́ngógó Owó Ọjà Àti Ìpààrọ̀ Owó Ilẹ̀ Òkèèrè Tí Ó…

  Ilé Ìfowópamọ́ Àpapọ̀ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti sọ pé ọ̀wọ́ngógó owó ọjà àti ìpààrọ̀ owó ilẹ̀ òkèèrè tí ó ti lọ sókè ni ìrètí wà pé yóò wálẹ̀ ní ọdún 2024 Gómìnà ilé ìfowópamọ́…

Àwọn Ilé Iṣé Nlá Nlá Pe Ìjọba Ìpínlẹ̀ Eko Láti Dẹ́kun Ìwà ìbàjẹ́ Láti Ọwọ́ Àwọn Oníṣẹ́ Láabi.

Ẹgbẹ́ àwọn ilé iṣé nla nlá ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti rawọ ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba ìpínlẹ̀ Eko lati Dẹkun ìwà ìbàjẹ́ láti ọwọ́ àwọn láabi. Wọn ní ìwà ìbàjẹ́ yìí n pa àwọn lára púpọ̀ nítorí o ṣe àkóbá nla fún dukia àti ilé iṣé. Ọ̀gá Àgbà…

Ilé Ìfowópamọ́ Àpapọ̀ Ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ti Pàṣẹ kíkójáde, Gbígbà Owó Àtijọ́…

Lójúnà àti tẹ̀lé ìdájọ́ Ilé Ẹjọ́ Àpapọ̀ ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó wáyé ní Ọjọ́rú, ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n osù kọkànlá níbi tí ilé ẹjọ́ ti gba ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ amòfin àgbà wọlé, èyí tí ó pè fún…

Ilé Ẹjọ́ Gíga Ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ti Fi Àyè Gba Níná Owó Náírà Àtijọ́ Àti…

Ilé Ẹjọ́ Gíga Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti fi àyè gba níná owó náírà tuntun àti ti àtijọ́ ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà èyí tí ó fagilé gbèdéke ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n osù kejìlá ọdún 2023 èyí tí ó ti wà…
button