Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ
This is a category for business news
Àjọ Tí Ó Ń Rí Sí Ìgbòkè-gbodò Ọkọ̀ Ojú Irin Bẹ̀rẹ̀ Ìrìnàjò Alẹ́
Àjọ tí ó ń rí sí ìgbòkè-gbodò ọkọ̀ ojú irin ti parí ètò láti bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò alẹ́ kí ó tó di ìpín kejì nínú ọdún 2024
Alákòóso àjọ náà, Fidet Okhiria ni ó sísọ lójú ọ̀rọ̀ náà níbi…
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Àti Orílẹ̀-èdè India Yóò Ni Ìbáṣepọ̀ Tó Dàn Mọ́rán Fún Ìdàgbàsókè Ìwàkusà Irin.
Láti rí wí pé Ìdàgbàsókè bá ètò ìwàkusa irin, Mínísítà fún ìdàgbàsókè ìwàkusa irin , Ọmọba Shuaibu Audu tí ṣe ìpàdé pẹ̀lú aṣojú ilé iṣé India nipa irin Ọgbẹni Mukesh Sharma.
Ìpàdé da lórí láti jiroro nípa bí ilé iṣé ìwàkusa irin yóò ṣe…
Nàìjíríà Tí Kéde Ipò Àgbàrá Látí Fọ̀ Èpò Rọbi Rẹ̀
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu tí kéde àwọn ìgbìyànjú pàtàkì kàn ìṣàkóso rẹ̀ láti gbé àwọn ilé-iṣẹ́ tó ń fọ́ èpò rọbi Nàìjíríà dìde ní ọdún 2024, bí tí ilé-iṣé tó ń fọ èpò ní Ìpínlẹ̀ Port Harcourt àti tí aladaani Dangote.
Ààrẹ náà tún sọ pé…
Ààrẹ Tinubu Búra Látí Gbé Ìgbésẹ Tó Yá Lórí Ètò Ìnáwó Àtí Owó-orí
Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu sọ pé ìṣàkóso rẹ̀ tí ń ṣiṣẹ́ takun-takun láti ríi dájú pé gbogbo àwọn ètò àtúnṣe ìnáwó àtí ètò Owó-orí ní wọ́n yóò rí dájú láti ṣé, kó lè fí ayé gbá àwọn oníṣòwò káàkiri Àgbáyé.
Ó sọ èyí dì mímọ̀ nínú ìkéde àti…
Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Yóò Sọ Àbà Ìsúná Ọdún 2024 Di Òfin Ní Ọjọ́ Àbámẹ́ta
Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Àgbà ti parí ètò láti sọ àbádòfin ìsúná ti ọdún 2024 di òfin ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọgbọ̀n ọjọ́ osù kejìlá ọdún 2024
Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu gbé àbá ìsúná tírílíọ̀nù…
Ẹgbẹ̀rún Mẹ́ta Àbọ̀ Náírà Ní Àpò Sìmẹ́ńtì Kan- Ilé Iṣẹ́ BUA fi Ìdí Ọ̀rọ̀ Múlẹ̀
Alága àti olùdarí ilé iṣẹ́ ìdókoòwò BUA, Abdul- Samad Rabiu sọ pé ilé iṣẹ́ náà yóò tẹ̀síwájú lórí àdéhùn rẹ̀ láti máa ta báàgì sìmẹ́ǹtì ní ẹgbẹ̀rún mẹ́ta àbọ̀ náírà bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kíní osù kíní…
Síse Àmójútó Àwọn Ẹka Ọrọ̀ Ajé Yàtọ̀ Sí Epo Rọ̀bì Yóò Pa Owó Wọlé Lọ́pọ̀ Yanturu-…
Alága Ìgbìmọ̀ Ìjọba Àpapọ̀ Lóri Ìpawówọlé Àti Àtúntò Owó Orí, Taiwo Oyedele sọ wípé Orílẹ̀-èdè Naijiria yóò rí tírílíọ̀nù Mẹ́wàá náírà ní ọdún kan ṣoṣo látàrí àmójútó àwọn ẹka ọrọ̀ ajé tí ó…
Mímú Ìgbòòrò Bá Ètò Ọrọ̀ Ajé Se Pàtàkì Fún Ìdàgbàsókè Orílẹ̀-èdè- Dapọ Abiọdun
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ogun, Ọmọba Dapọ Abiọdun ti pè fún mímú ìgbòòrò bá ètò ọrọ̀ ajé èyí tí yóò se àmójútó Ètò Ọ̀gbìn, Ìmọ̀ Ẹ̀rọ, Ìdàgbàsókè ohun Àlùmọ́ọ́nì àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ
Ó sàlàyé pé…
Dan-dan Ni Kí Owó Ìrànwọ́ Ìjọba Àpapọ̀ Kárí -Ilé, Kárí-Oko- Báńkì Àpapọ̀ Àgbáyé
Ìpín péréte nínú àwọn aláìní tí ìjọba fojúsùn ni ó sẹ̀ṣẹ̀ gba owó ìrànwọ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dọ́ọ́gbọ̀n ní osù kan tí ìjọba se àgbékalẹ̀ rẹ̀
Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ nípa ètò ọrọ̀ ajé tí Báńkì Àgbáyé fún…
Àbádòfin Ètò Ìsúná Ọdún 2024 Yóò Di Òfin Ní Ọgbọ̀n Ọjọ́ Osù Kejìlá- Adarí Ilé…
Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin, Ọnọrébù Tajudeen Abbas sọ pé àbádòfin ètò ìsúná Ọdún 2024 yóò jẹ́ bíbuwọ́lù ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọgbọ̀n ọjọ́ osù kejìlá, ọdún 2023
Ó fi ọ̀rọ̀ náà léde nígbà tí àwọn ọmọ…