Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ

This is a category for business news

Ilé ìfowópamọ́ Àgbáyé Pè Fún Àwọn Àtunṣe Ìgbékalè Láti yọ Àwọn ọmọ Nàìjíríà…

Ẹgbẹ́ ilé ìfowópamọ́ Àgbáyé sọ  pé ìgbékalẹ̀ àtúnṣe tí ó jinlẹ̀ ṣe pàtàkì ní kíákíá  láti yọ àwọn mílíọ̀nù  ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kúrò nínú ìpọ́njú,ó kìlọ̀ pé  ìdá mẹ́tàdín-lógún  àwọn…

Ìjọba Nàìjíríà Ń Gbìyànjú Láti Ṣe Ìṣelọ́pọ̀ Súgà Láàrín Ọdún Mẹ́wàá Láti Ìgbà…

Ìjọba Nàìjíríà sọ pé ó ní èròǹgbà láti ṣe àṣeyọrí lórí ìṣelọ́pọ̀ súgà láàrín ọdún mẹ́wàá láti ìgbà yìí. Mínísítà fún  Ìṣòwò àti Ìdókò-òwò, Niyi Adebayo ṣe àfihàn yí ní ìlú Abuja ní…

Ilé-iṣẹ́ Sìmẹ́ńtì Dangote : Ọjà yóò wà káàkiri lárọwọ́tó Àwọn fún ọmọ Nàìjíríà

Ilé-iṣé Sìmẹ́ńtì Dangote  ti fi dá àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lójú pé ọjà yóò wà lọ́pọ̀ àti lárọwọ́tó wọn,pàápàá jùlọ lásìkò yìí tí ó ń jinlẹ̀ si láti ṣe dééd́éé lórí  ọjà rẹ̀ àti títàn si.…

Àwọn aṣojú tí ó ní ìwé-àṣẹ nìkan ni yóò le ra ọjà tààrà láti ọ̀dọ̀ àwọn àgbẹ̀…

Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ àpapọ̀ (FEC) ti fọwọ́sí pé àwọn aṣójú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nìkan tí ó ní ìwé-àṣẹ ni yóò le ra ọjà tààrà láti ọ̀dọ̀ àwọn àgbẹ̀ àti títà fún àwọn àjèjì. Ifọwọsi yii waye nibi ipade  …

Ìjọba Àpapọ̀ Bu Ọwọ́ Lu Àdéhùn (MOU) Pẹ̀lú Ilé-Iṣẹ́ Huawei Technologies Nigeria Limited…

Ìjọba àpapọ̀ àti ilé-iṣẹ́ Huawei Technologies Nigeria Limited ti fọwọ́ sí ìwé àdéhùn kan (MoU) lórí Ìmọ̀-ẹ̀rọ Ìbáraẹnisọ̀rọ̀ (ICT) láti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àti  ìdánilókòwò fun ẹgbẹrun  òsìsẹ́ ìjọba jakejado orilẹ…
button