Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ

This is a category for business news

Ọmọ ẹgbẹ́ Ilé-Aṣòfin Nàìjíríà Pẹ̀lú Àjọṣèpọ̀ àjọ tí kìí ṣe tìjọba gbìmọ̀ Láti fún…

Ọ̀kan lára àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣojú-ṣòfin, Alhaji Balarabe Salame (APC-Sókótó) ti ṣe agbátẹrù ìdánilẹ́ẹ̀kọ́ fún àwọn ọ̀dọ́ mẹ́tà-lé-lójì-dín-lẹ́gbẹ̀ta lórí orísirísi ètò ìmò ìṣe ní Sókótó. Salame, ọmọ…

Àwọn ènìyàn wá wọ̀rọ̀kọ̀ fi ṣàdá lórí ọ̀wọ́n gógóo gáásì ìdáná … Àwọn…

Lílo  Gáàsì ìdáná Àdáyébá (LPG) ti lọ sílẹ̀ jákèjádò orílẹ̀-èdè. Aarẹ, Ẹgbẹ oni Gaasi ni Naijiria, Ed Ubong, sọ lakoko apejọ  kan ni Ilu Eko, pe gaasi  lilo ọdọọdun orilẹ-ede  lọwọlọwọ bayii jẹ 1.3mn ati 1.5mn mẹtiriki…

Ilé ìfowópamọ́ Àgbáyé Pè Fún Àwọn Àtunṣe Ìgbékalè Láti yọ Àwọn ọmọ Nàìjíríà…

Ẹgbẹ́ ilé ìfowópamọ́ Àgbáyé sọ  pé ìgbékalẹ̀ àtúnṣe tí ó jinlẹ̀ ṣe pàtàkì ní kíákíá  láti yọ àwọn mílíọ̀nù  ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kúrò nínú ìpọ́njú,ó kìlọ̀ pé  ìdá mẹ́tàdín-lógún  àwọn…
button