Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ
This is a category for business news
Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Pè Fún Àtúnṣe Pápákọ̀ Òfurufú Ilẹ̀ Nàìjíríà
Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ti wá ojútùú sí ìpèníjà tí ó ń kojú pápákọ̀ òfurufú. Wọ́n pè ìpè náà níbi ìpàdé àpapọ̀ pẹ̀lu Mínísítà Hadi Serika àti àwọn ikọ̀ tí ó ń darí ọkọ̀ òfurufú ní abẹ́lé.
…
A jẹ́rìí sí títa ilé-ìfowópamọ́ polaris
Ilé ìgbìmọ̀ aṣojú ṣòfin fìdíi títa ilé-ìfowópamọ́ọ Polaris múlẹ̀ pé ó tẹ̀lé ìlànà àti pé ààrẹ lọ́wọ́ si
Alága, ìgbìmọ̀ tó ń ṣe ìwádìí títa ilé-ìfowópamọ́ náà, Ọ̀gbẹ́ni Henry Nwawba jẹ́rìsíi…
Orílẹ̀ Èdè Ethiopia Ti Fi Gbèdéke Sí Lílo Owó Ilẹ̀ Òkèèrè
Orílẹ̀ èdè Ethiopia ti fi òfin de fífún àwọn tí ó ń kó ọjà wọlé láti ilẹ̀ òkèèrè ní àǹfààní láti gba owó ilè òkèèrè lójúnà àti dènà kíkó àwọn ohun èlò tí kò se ọrọ̀ ajé orílẹ̀ èdè náà ní…
Adarí Ilé Ìfowópamọ́ Àpapọ̀ Nàìjíríà Gba Àmì Ẹ̀yẹ Àgbáyé
Ọ̀gá àgbà ilé ìfowópamọ́ àpapọ̀, Ọ̀gbéni Godwin Emefiele ti gba àmì ẹ̀yẹ onímọ̀ ìgbàlódé jùlo ní ilẹ̀ adúláwọ̀ nípa ètò ìfowópamọ́ ti ọdún 2022 tí àjọ onísòwò àgbáyé kan fún-un.
Ó gba àmì…
Àdéhùn Láàrín Russia Àti Àjọ Àgbáyé (UN) Lórí Ọjà Òkèèrè
Russia tí fí ìwé ẹdun ọkàn nípa ìwé ìṣẹ́ àdéhùn ọjà òkèèrè tí Black Sea Grain sí Àjọ Àgbáyé (United Nations).
Gennady Gatilov, aṣojú Russia sí United Nations, sọ pé “Ta bá ríi pé kò sí àtúnṣe sí ìwé àdéhùn náà, lórí ètò àwọn ọkà ati…
Ẹka Kárà-kátà Àgbáyé Ti Pè Fún Ìbásepọ̀ Pẹ̀lú Ibùdókọ̀ Ojú Omi Nàìjíríà
Ẹka kárà-kátà àgbáyè kan ti pè fún àjọsepọ̀ tí ó dán mánrán pẹ̀lú àjọ tí ó ń se àkóso ọkọ̀ ojú omi Nàìjíríà láti mú àlékún bá ọrọ̀ ajé ilẹ̀ Áfíríkà.
Alákoso àjọ náà, ọ̀gbẹ́ni Segun…
SON Ṣé Tán Láti Gbógun Tí Àwọn Ilé-isé Tó Ń Pèsè Òun Ayédèrú
Àjọ Standards Organisation of Nigeria, SON, ẹka ìpínlẹ̀ Anambra, gúúsù ìlà-òòrùn Nàìjíríà, tí ṣetán làti gbá Iwe-ẹri Mandatory Conformity Assessment Programme (MANCAP) eyikeyi olupese awọn òún elo ọja kékeré ni ìpínlẹ̀ náà.
Alákóso…
Ìpàtẹ ọjà káríayé ẹlẹ́ẹ̀kẹtà-dínlógún bẹ̀r̀ẹ
Ìpàtẹ ọjàẹlẹ́ẹ̀kẹtàdín-lógún ti Oníṣòwò Àgbáyé nílùú Abuja tí ilé iṣẹ́ títà rírà àti Ilé-iṣẹ́ okòwò Àbújá (ACCI) ti bẹ̀rẹ̀, ní òpin ọ̀sẹ̀, ní pápá ìtajà oníṣòwò tí ó wà ní olú-ìlú.
Gbólóhùn kan ti oṣisẹ ACCI fun eto…
Ètò Ti Parí Fún Ìpèsè Iyọ̀ Lọ́pọ̀ Yanturu
Ìjọba àpapọ̀ ti bu ọwọ́ lu bílíọ̀nù kan ó lé díẹ̀ láti fi dáàbò bo pípàdánù iyọ̀, léyìí tí yóò mú pípèsè iyọ̀ lọ́pọ̀ yanturu. Èyí pèpè fún mímọ ògiri láti fi dáàbò bo iyọ̀ ní ìpínlẹ̀ Ebonyi.
…
Mínísítà Gbé Oríyìn Fún Dídá Ilé Isẹ́ Sílẹ̀ Ní Ìlú Calabar
Wọ́n ti se àpèjúwe dídá ilé isẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà kan gbógì láti gba àwọn ènìyàn sísẹ́, wíwá ọ̀nà àtijẹ àti lílé ìsẹ́ wọ ìgbẹ́ fún àwọn ènìyàn ìlú Calabar, ìpínlẹ̀ Cross River.
…