Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ
This is a category for business news
Bánkì Àgbáyé Buwọ́lù Ètò Ẹyàwó Orílẹ̀-èdè China Látí Ṣé Àtìlẹ́yìn Ìṣẹ́ Ọ̀gbìn Ìrẹ́sì lọpọ̀lọpọ̀
Bánkì Àgbáyé tí fọwọ́sí ẹyàwó tí ọ̀ọ́dúrún dín díẹ̀ mílíọ̀nù dọla ($255m) látí ṣé àtìlẹ́yìn ètò tí yóò ṣé àdínkù eruku, tí yóò sí rán àwọn àgbẹ lọ́wọ́ lórí iṣẹ́ ọ̀gbìn Ìrẹ́sì ní àárín gbùngbùn China.
Olùdarí Àgbà kàn ní Bánkì Àgbáyé…
Iṣẹ́ Kíkọ́ Ti Lé Òsì Wọ̀gbẹ́ Fún Àwọn Ọ̀dọ́ Ní Ìpínlẹ̀ Anambra
Ìjọba ìpínlẹ̀ Anambra ti fi ọwọ́ si iwe àdéhùn pẹlu ijọba àpapọ̀ lati ọwọ́ Ẹka Òṣìṣẹ́ àti Ìgbaniṣíṣẹ́ lati mu alekun ba iṣẹ ọwọ́ ni kíkọ́ ní ìpínlẹ̀ Anambra.
Gomina Chukwuma Soludo, ẹni ti Kọmísánnà Ìdàgbàsókè…
Alága Ìsàkóso Ètò Ìgbágbárawọni Peregedé- Ìjọba Àpapọ̀
Ìjọba Àpapọ̀ Orilẹ-ede Naijiria lu alákòsóo àgbà fún ètò Owó Ìkọ́ṣẹ́, Ọ̀̀gbẹ́ni Joseph Ari lọ́gọ ẹnu fún iṣẹ́ takun-takun àti jíjẹ́ olóòtọ́ láti mú ìgbé ọmọnìyàn rọrùn lásìkò àti lẹ́yìn wàhálà àrùn…
Ẹgbẹ́ Agbéróyìn Sáfẹ́fẹ́ Ilẹ̀ Áfíríkà AUB Gbóríyìn Fún Ilé-iṣẹ́ Satẹlaiti Tí Nàìjíríà
Ẹgbẹ́ Agbéróyìn sáfẹ́fẹ́ ilẹ̀ Áfíríkà (African Union of Broadcasting AUB) tí gbóríyìn fún ilé-iṣẹ́ Satẹlaiti tí Nàìjíríà (Nigeria Communications Satellite, NIGCOMSAT Ltd) ní bí wọ́n ṣé ń ṣiṣẹ́ dojú ìwọn.
Olùdarí Gbogbogbò tí Ilé-iṣẹ́…
Olùdásílẹ̀ ilé ìfowópamọ̀ FCMB, Subomi Balogun di olóògbé
Olùdásílẹ̀ ilé ìfowópamọ̀ FCMB, Subomi Balogun di olóògbé.
ìròyìn lẹ́kùnúnrẹ́rẹ́ ń bọ̀ lórí rẹ̀̀ láìpẹ́
Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Ń Pépé Fún Ìtùsílẹ̀ Àwọn Ìnáwó Ọkọ Òfurufú
Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí rawọ ẹ̀bẹ̀ sí awọn ilé-iṣẹ́ ọkọ Òfurufú káríayé látí má ṣé daṣẹ́ dúró làkókò tí àwọn àkitiyan ń lọ́ lọwọ́ láti yanjú àwọn ìdíwọ́ tó ń ṣókùnfá ìdìnà ìnáwó àwọn ọkọ òfurufú lórílẹ̀-èdè yìí.…
Ìgbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Yìí Rọ́ Àwọn Àdári Ilé-ẹ̀kọ́ Gíga Nàìjíríà Látí Ṣé Ìpolongo Ilé-ìwé Wọ́n
Ìgbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo tí rọ́ àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga ní Nàìjíríà látí ṣiṣẹ́ takuntakun fún ìgbéga àtí ọnà àtí máà gbá owó wọlé fún àwọn ilé-ẹ̀kọ́ wọnyí nítori wípé kò sí Orílẹ̀-èdè kàn lágbayé tó lé ṣé ètò…
Iréwọlédé látàrí Bí Ilé Ìfowópamọ́ Àpapọ̀ Se Mú Ìgbòòrò Bá Ìpèsè Owó Ilẹ̀…
Gómìnà Ilé Ìfowópamọ́ Àpapọ̀ Ilẹ̀ Nàìjíríà, Godwin Emefiele sàlàyé pé ìmúgbóòrò yóò bá ìpèsè owó ilẹ̀ òkèèrè gẹ́gẹ́ bí ojúse pàtàkì fún àwọn ilé ìfowópamọ́.
Emefiele sàlàyé ọ̀rọ̀…
Ààrẹ Buhari Yóò Se Ìfilọ́lẹ̀ Ilé Iṣẹ́ Ìfọpo Dangote Ní Ọjọ́ Kejìlélógún Osù Kaàrún
Ààrẹ Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari yóò se ìfilọ́lẹ̀ Ilé Iṣẹ́ ìfọpo èyí tí Aliko Dangote dá sílẹ̀, ní ọjọ́ kejìlélógún osù kaàrún ọdún 2023
Olùrànlọ́wọ́ sí Ààrẹ, Bashir Ahmed sàlàyé…
Ìbásepọ̀ láàrin Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà Àti Canada Lágbára si Lójúnà Àti Mú…
Ìjọba orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ti fi ìlàkààkà rẹ̀ léde lójúnà àti jẹ́ kí ìbásepọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú orílẹ̀ èdè Canada fìdí múlẹ̀ sinsin láti mú ìgbòòrò bá ọrọ̀ ajé tí yóò sì se okùn-ǹ-fà fún ìdàgbàsókè…