Take a fresh look at your lifestyle.

Bánkì Àgbáyé Buwọ́lù Ètò Ẹyàwó Orílẹ̀-èdè China Látí Ṣé Àtìlẹ́yìn Ìṣẹ́ Ọ̀gbìn Ìrẹ́sì lọpọ̀lọpọ̀

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 472

Bánkì Àgbáyé tí fọwọ́sí ẹyàwó tí ọ̀ọ́dúrún dín díẹ̀ mílíọ̀nù dọla ($255m) látí ṣé àtìlẹ́yìn ètò tí yóò ṣé àdínkù eruku, tí yóò sí rán àwọn àgbẹ lọ́wọ́ lórí iṣẹ́ ọ̀gbìn Ìrẹ́sì ní àárín gbùngbùn China.

Olùdarí Àgbà kàn ní Bánkì Àgbáyé èyí tó ń ṣoju Orílẹ̀-èdè China, Mongolia àti Korea, Mara Warwick sọ pé àwọn òwò náà yóò tún wúlò fún ìlọsíwájú àwọn iṣẹ́ idominugere ní àwọn Oko Ìrẹ́sì naa.

Tún kà nípa:China Ṣetán Látí Ṣé Àtìlẹ́yìn Àlà Àwọn Ọ̀dọ̀ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Gẹ́gẹ́ bí ilé ìfówópámọ́ náà ṣé sọ, ètò náà yóò ṣé ifọkanbalẹ ati igbelarugẹ ojú-ọjọ́ ní àwọn àgbègbè ìgbèríko, tí yóò tún ṣé àdínkù èéfín àti pèsè iṣẹ́ lọpọ yanturu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button