Browsing Category
ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ
This is a category for business news
Àfikún Orí Owó Yóò Tó Ìdá Mẹ́ẹ̀dọ́ọ́gbọ̀n Nínú Ọgọ́rùn-ún Látàrí Yíyọ Ìrànwọ́…
Báńkì Àgbáyé ti fi àríwòye léde wípé, ó se é ṣe kí àfikún orí owó lọ sókè tí yóò sì tó ìdá mẹ́ẹ̀dọ́ọ́gbọ̀n nínú ọgọ́rùn-ún ní ọdun 2023 latari yiyọ iranwọ ori epo.
Àtẹ̀jáde àfojúsùn náà wáyé…
ọ̀wọ́ngógó gógó ẹran àgbò mú kí àwọn ènìyàn gba ìsọ̀ alápatà lọ láti lọ pin ẹran…
Bí pọ̀pọ̀sìnsìn ọdún iléyá se ń lọ lọ́wọ́ ní káàkiri gbogbo àgbáyé, se ni ó dà bí ẹni pe púpọ̀ nínú àwọn mùsùlùmí tó nífẹ̀ẹ́ láti ra ẹran àgbò ọdún yìí fún pípa ni wọ́n bá ìjákulẹ̀ pàdé lórí bí…
Ọlọ́jà Àgbò Àti Àwọn Awakọ̀ Ké Gbàjarè Nítorí Àìtà Ọjà Ní Ìpínlẹ̀ Kano
Ní wákàtí díẹ̀ sí àyájọ́ Ọdún iléyá, àwọn tí ó ń ta ẹran àgbò àti àwọn ọlọ́kọ̀ ti fi àìdùnnú ọkàn hàn látàrí àì-sí àwọn oníbàárà fún ọjà wọn ní ọdún yìí.
Àwọn olùwòye sọ wípé, kò…
Nàìjíríà Ṣetán Láti Tẹ́wọ́gba Olùdókòwò – Ààrẹ Tinúbú
Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bọ́lá Tinúbú sọ pé àtúnṣe tó ń lọ lọ́wọ́ ní orílẹ̀-èdè yìí bẹ̀rẹ̀ láti ìmúkúrò owó ìrànwọ́ orí epo, títọ́ ti pàsípàrọ̀ owó ilẹ̀ òkèèrè yóò duro dáradára fún ọrò ajé orílẹ̀-èdè yìí kò le tẹ̀wọ̀n sí, kí ó le…
A ti ṣe ìdókòwò Irínwó Bílíọ̀nù Dọ́là ní Nàìjíríà – Ilé-iṣẹ́ ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀
Ilé-iṣẹ́ ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀, Barthi Airtel sọ pe oun ti ṣe ìdókòwò Irínwó Bílíọ̀nù Dọ́là lati igba ti ile-iṣẹ naa ti bẹrẹ iṣẹ ní Nàìjíríà.
Alaga Barthi Airtel, Sunil Mittal, sọ eyi di mimọ nigba ti o n ba awọn…
Àjọ Nec Ń Fẹ́ Àtìlẹ́yìn Amòfin Fún Ilé Isẹ́ Ọkọ̀
Àjọ National Economic Council(NEC) ti pé ìpè fún ìbuwọ́lù Ìdàgbàsókè Ilé Iṣẹ́ Ọkọ̀ ti Àpapọ̀ láti ọwọ́ ilé Ìgbìmọ̀ aṣòfin orílẹ̀-èdè yìí.
Eléyìí yóò fi Nàìjíríà sí ipò tó yẹ, yóò sì dàrí olùdókòwò láti òkè òkun wá sí…
Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Àti Nertherland Ti Gbé Ìgbésẹ̀ Akin Láti Se Ìmúgbòòrò Ètò…
Ìgbésẹ̀ ti wáyé láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ọrọ̀ ajé láàrin Orilẹ-ede Naijiria ati Nertherland lójúnà àti mú àlékún bá ìgbáyégbádùn Orilẹ-ede mejeeji naa.
Níbi àpérò nípa ètò ọrọ̀ ajé…
Ẹ Dá Ìgúnpá Orí Epo Padà Tàbí Kí Ẹ Dojúkọ Ìsòro Ìdaṣẹ́sílẹ̀- Ẹgbẹ́ Òsìṣẹ́ Fi Ohùn…
Ẹgbẹ́ Òsìṣẹ́ ní Orílẹ̀-èdè Naijiria ti kilọ fun ìjọba àpapọ̀ láti yi ìpinnu rẹ̀ padà lórí yíyọ ìgúnpá orí epo, bíkòjẹ́ bẹ́ẹ̀, ìjọba yóò dojúkọ ìsòro ìdaṣẹ́sílẹ̀ èyí tí ìrètí wà pé yóò bẹ̀rẹ̀ ní Ọjọ́bọ̀…
Ẹgbẹ́ Onísòwò Ìpínlẹ̀ Nasarawa Gbóríyìn Fún Gómìnà Sule Fún kíkọ́ Ọjà Ìgbàlódé
Ẹgbẹ́ Onísòwò ìpínlẹ̀ Nasarawa ti lu Gomina Sule lọ́gọ ẹnu fún kikọ ọjà igbalode ní ijọba ìbílẹ̀ mẹta ní ìpínlẹ̀ naa.
Ẹgbẹ́ náà fí ọ̀rọ̀ ìdúpẹ́ léde nígbà tí ó ń se àyípadà ìwé òfin rẹ ní ìlú Lafia,…
Àwọn Òsìṣẹ́ Ojú Omi Yóò Bẹ̀rẹ̀ Ìyansẹ́lódì Ní Ọjọ́ Ajé
Ẹgbẹ́ àwọn òsìṣẹ́ ojú omi ní Orilẹ-ede Naijiria ti parí ètò lati gùnlé ìyanṣẹ́lódì ní ọjọ Ajé látàrí ìgbé ayé tí ó kù díẹ̀ kààtó fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ àjọ náà.
Alága àpapọ̀ ẹgbẹ́ náà, Adewale…