Take a fresh look at your lifestyle.
Browsing Category

ÌRÒYÌN ÌDÓKOÒWÒ

This is a category for business news

Ìjọba Àpapọ̀ Ti Gbáradì Láti Mú Àlékún Bá Ìpèsè Epo Rọ̀bì Lójúnà Àti Tán Ìsòro…

Mínísítà Kejì Fún Ọ̀rọ̀ Epo Rọ̀bì ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Heineken Lokpobiri ti sàlàyé pé mímú àlékún bá ìpèsè epo rọ̀bì jẹ́ ọ̀nà àbáyọ láti tán ìsòro ọ̀wọ́ngógó epo rọ̀bì ní Orílẹ̀-èdè…

Àjọ Tí Ó Ń Pèsè Iná Mọ̀nàmọ́ná Ti Parí Ètò Láti Mú Iná Dé Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Àyè Ní ọdún…

Àjọ tí ń pèsè iná mọ̀nàmọ́ná fún ìgbèríko ti parí ètò láti mú iná dé gbogbo àyè tí ó yẹ pẹ̀lú àwọn àlàkalẹ ètò tí yóò mú kí isẹ́ náà kẹ́ṣẹ járí.   Alákòóso fún ètò náà, Mutari Ibrahim ni…

Ààrẹ Nàìjíríà yan Ajẹ́rìí ìwé ìṣirò owó gbogbogbòò fún ìjọba àpapọ̀

Ààrẹ Nàìjíríà, Bọla Tinubu ti buwọ́lu yíyan Ọ̀gbẹ́ni Shaakaa Chira gẹ́gẹ́ bíi Ajẹ́rìí ìwé ìṣirò owó gbogbogbòò pàtàkì fún ìjọba àpapọ̀, gẹ́gẹ́ bí ìgbìmọ̀ òṣìṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ (FCSC), ṣe fàá kalẹ̀. Alaye…

Ilé Iṣẹ́ Bua Gé Owó Sìmẹ́ǹtì Lọ Sílẹ̀ Ṣí Ẹgbẹrún Mẹ́ta Ààbọ̀ Náírà

Ile iṣẹ to n se cement -BUA ni alẹ́ àná kéde lílọ sílẹ̀ iye owó ti wọn ń ta Sìmẹ́ǹtì láti ẹgbẹ̀run màrún/mẹ́fà sí Ẹgbẹ̀rún Mẹ́ta Ààbọ̀ Náírà fún báàgì kan láti òní lọ. Nínú akọsilẹ kan ti awọn alábójútó ilé ìṣẹ́ buwọ́lù, wọn sì gée, wọn…
button