Browsing Category
ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ
This is a category for Africa news
DR Congo, Rwanda Pè Fún Ìdáwọ́ Ogun Dúró
Ààrẹ orílẹ̀-èdè olómìnira Congo, Félix Tshisekedi àti ti orílẹ̀-èdè Rwanda, Paul Kagame ti pè ipe ìdáwọ́ogun dúró ní ìlà oòrùn DR Congo ní kíámọ́sá lẹ́yìn ìpàdé wọn tó wáyé ní Qatar.
Ó jẹ ìgbà àkọkọ ti àwọn olórí méjèèjì náà yòo se ìpàdé…
Àjọ ECOWAS Pè Fún Níná Owó Kan Ṣoṣo Ní Iwọ̀ Òrùn Adúláwọ̀
Mínísítà Fún Ètò Ìnáwó àti Gómínà Báńkì Àpapọ̀ àwọn Orílẹ̀-èdè àjọ ECOWAS ni ó ti pè fún ìdásílẹ̀ owó kan ṣoṣo fún àjọ náà èyí tí yóò se àmúgbóòrò ètò ọrọ̀ ajé àti ìgbáyégbádùn…
Ìwọ̀n Ilé Isẹ́ Tó Ń Se Àwọn Nǹkan Ní Ilẹ̀ South Africa Bẹ̀rẹ̀ Sí Ní Lọlẹ̀
Ìwọ̀n àwọn Ilé Isẹ́ to ń se àwọn nǹkan Ni Ilẹ̀ South Africa bẹ̀rẹ̀ sí ni já wálẹ́ láti oṣù Kejì ọdún yìí bi purchasing managers’ index, PMI, ti ìbílẹ̀ se sọ ni ọjọ́ Ajé.
PMI alátúnse àtìgbà dé ìgbà ti Bánkì ilẹ̀ South Africa -…
Àjọ AIU Sọ Fún Ehoro Orí Ọ̀dàn Ọmọ Bíbí Kenya, Kipkorir Láti Lọ Rọ́kú Nílé Fún Ìgbà Kan
Ehoro orí ọ̀dàn ọmọbíbí ilẹ Kenya, Brimin Kipkorir ní wọ́n ti sọ fún kí ó lọ rọ́kú nílé fún Igba kan náà látàrí pè ō lulèẹ̀ ìdánwò mímu ògùn olóró tí wọ́n se fun. Àjọ Athletics Integrity Unit (AIU) ló sọ èyí.
Ọgbẹni Kipkorir…
Bukavu: Elétò Ààbò Tó Lè Nígba Darapọ̀ Mọ́ Ikọ̀ M23
Ó ti lé Nígba àwọn Ọlópàá àti Sójà tó ti lọ darapọ̀ mọ́ ikọ̀ Alliance Fleuve Congo (AFC/M23), ikọ̀ ọlọ̀tẹ̀ ní ìlà oòrùn orílẹ̀-èdè náà - orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ Congo.
Ayẹyẹ ìdarapọ̀ náà wáyé ní iwájú Gbọ̀ngàn adarí Ilé Iṣẹ́…
Ìbọn Sekúpa Elétò Ìlera Ní Orílẹ̀-èdè Congo
Olùrànlọ́wọ́ ọmọnìyàn kan ti pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ látàrí bí ìbọn se bá a nibi làásìgbò tí ó ń wáyé níbi tí Orílẹ̀-èdè Rwanda ti se ìrànlọ́wọ́ fún àwon ọmọ ogun ọlọ̀tẹ̀ tí wọn sì ti gba ìlú méjì pẹ̀lú…
Àwọn Aṣòfin Nàìjíríà Yóò Tẹ̀síwájú Nínú Àjọṣepọ̀ Ìdàgbàsókè Pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Kenya
Ilè Ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣofin yóò tẹ̀síwájú nínú àjọṣepọ̀ wọ́n pẹ̀lú Kenya lórí ìdàgbàsókè àwọn apá pàtàkì tí ètò-ọrọ àjé.
Alága, Ẹgbẹ́ Ilé aṣòfin Orílẹ̀-èdè méjèèjì, Ọ̀gbẹ́ni Abdullahi El-rasheed, fúnni ní ìtọ́kasí ní ìpàdé kán pẹ̀lú…
Ìròyìn Ayọ̀: Àrùn Ebola Di Ohun Àfìsẹ́yìn Tí Egúngún Ń Fi Asọ Ní Orílẹ̀-èdè Uganda-…
Ènìyàn mẹ́jọ tí àyẹ̀wò fi hàn pé àrùn Ebola ń yọ lẹ́nu nígbà tí àrùn náà súyọ ní ọ̀ṣẹ̀ tí ó kọjá ní ó ti wà ní ipò àlàáfíà, tí wọn si ti kúrò ní ilé ìwòsàn
Àjọ WHO gbósùbà fún ìjọba…
Wàhálà Ńlá Bẹ́ Sílẹ̀ Ní Orílẹ̀-èdè Congo, Ọ̀pọ̀ Ènìyàn Sá Àsálà Fún Ẹ̀mí Wọn
Látàrí wàhálà ńlá tí ó ń wáyé ní Orílẹ̀-èdè Congo, àwọn ará ìlú ti ń sá ní kẹ̀tí-kẹ̀tí lọ sí Burundi fún ìdáàbò bò ẹ̀mí wọn
Ní ọ̀ṣẹ̀ tí ó kọjá, ìjọba Orílẹ̀-èdè Burundi fi léde pé àwọn…
Kò sí Ìfọ̀kànbalẹ̀ Ní Zamzam, Orílẹ̀-èdè Sudan Látàrí Rúkè-rúdò Tí Ó Ń Wáyé-…
Agbẹnusọ akọ̀wé àpapọ̀ àjọ àgbáyé ti sàlàyé pé rúkè-rúdò tí ó ń wáyé ní Orílẹ̀-èdè Sudan ti fa ìdààmú dààbo, àìfàyàbalẹ̀ ọkàn, tí ó sì mú kí ìgbé ayé le koko ní àgbègbè náà
…