Browsing Category
ÌRÒYÌN ILẸ̀ ÀFÍRÍKÀ
This is a category for Africa news
Àwọn Oníṣòwò Adìẹ Tí South Africa Dìde Pàdà Lẹyìn Àìsàn Tó Pá Àwọn Adìẹ
Ilé-iṣẹ́ oníṣòwò adìẹ tó tóbi jùlọ ní South Africa 'Astral Foods' tó bẹ̀rẹ̀ ìgbà túntún yóò pàdà síi jèrè ní ìdajì-ọdún sí ìparí Oṣù Kẹ́ta bí wọ́n ṣé kojú àjakalẹ-àrun tó pá ọ̀pọ̀lọpọ̀ adìẹ àti iná mọ̀nàmọ́ná tó ń ṣé sege-sege ní…
Ẹgbẹ̀rún ènìyàn sá àsálà bí àwọn ọmọ ogun Israeli ṣe súnmọ́ Gúsù Gaza
Bí ìjà náà ṣe ń gbilẹ̀ si ní Gúsù ìlú Gaza tí Khan Yunis, ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ọmọ Palestine ń gbéra súnmọ́ Rafah lẹ́gbẹ́ẹ ààlà Egypt, tí wọ́n sì ń gbé àwọn nǹkan wọn tí wọ́n le gbé.
Awọn ọmọ ogun Israeli ti paṣẹ…
Àwọn Olùfẹ̀hónúhàn Wọ́de Tako Ìfìyàjẹ Obìnrin, Wọ́n Pè Fún Ìdájọ́ Òdodo
Àwọn olùfẹ̀hónúhàn ní Orílẹ̀-èdè Kenya tú yááyá sí òpópónà láti pè fún fífi òpin sí ìfìyàjẹ obìnrin, fífún obìnrin ní ẹ̀tọ́, ní papàá jùlọ àwọn tí ó ní ìpèníjà ara
Esther Passaris, tí ó…
Ẹ̀pa Ò Gbóró Fún Orílẹ̀-èdè Cameroon, Bí Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà Ṣe Lé Wọn Padà Lọ Sí Ìlú Wọn Pẹ̀lú…
Super Eagles àti Àwọn agbabọọlu Cameroon tí a tun mọ wọn sí Indomitable Lion bẹrẹ ere bọọlu ti ipele ofìdí rẹmi, o gba ilé rẹ̀ẹ lọ ti ẹlẹyinbo n pe n Knock Out ní dede aago mẹsan-an alẹ́
Ajayi ọmọ ẹgbẹ́ Agbábọ̀ọ̀lù Super Eagles lo…
Akọ̀wé America Yín Ìbáṣepọ̀ Orílẹ̀-èdè Rẹ̀ Pẹ̀lú Angola
Akọ̀wé tí America Antony Blinken tí yín ìbáṣepọ̀ láàrín Orílẹ̀-èdè America àti Orílẹ̀-èdè Angola, Ó sọ pé ìbáṣepọ̀ náà tí dé ibì gíga, Ó sọ èyí làkókò àbẹwò rẹ̀ sí Luanda.
Blinken sọ pé òun tí jíròrò lórí rògbòdìyàn tó wà láàrín Rwanda…
Ìdíje AFCON Ọdún 2023: Ivory Coast Yọ Akọ́ni-mọ̀ọ́gbá Jean-Louis Gasset Bí Ẹni Yọ Jìgá Lẹ́nu Isẹ́ .
Wọ́n ti fi ọ̀nà ita hàn Jean-Louis Gasset to jẹ akọ́ni-mọ̀ọ́gbá ilẹ̀ Ivory Coast latari ayo merin sí (4-0 ) ti ikọ̀ Ivory Coast pàdánù sí ọwọ́ ikọ̀ Equatorial Guinea ni ibi idije AFCON to n lọ lọwọ.
Eléyìí jẹ́ ìṣubú nla ninu ìtàn ere…
Atamátàsé Ziyech Jẹ́ ki Ikọ̀ Morocco Borí Bí Ikọ̀ Zambia Se Nkógbá Wọlé
Ikọ̀ Morocco fi ata sí ojú ikọ̀ Zambia pẹlú ayo kan dondo sí òdo (1-0) ni ọjọ Ojoru ni ibi idije Africa Cup of Nations (AFCON) to n lọ lọwọ ti won sì lọ sókè tente tabili ni isori F, èyí rán ikọ̀
Ivory Coast lati pada sinu ìdíje…
Ikọ̀ Tunisia Kúrò Ní Ìdíje AFCON Lẹ́yìn Tí Wọ́n Gbá Ọ̀mìn Pẹ̀lú Ikọ̀ South Africa
Ikọ̀ Tunisia tó wà ní ipò kẹta nínú ikọ̀ to dára ninu ere bọọlu ni ilẹ adulawo ti jade kuro ninu idije AFCON leyin ọ̀mìn alaileyelewo(0-0) ti wọ́n gbá pẹlú iko South Africa ni isori E ni ọjọ́ Ojoru.
Ikọ̀ Ariwa adulawo náà ni…
Ìdíje AFCON Ọdún 2023: Ipele Ẹlẹ́ni mẹ́rìndínlógún (Round Of 16 Fixtures)
Ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n, oṣù kínní :
1: Angola vs Namibia (Bouake, Aago márùn ún ìrọ̀lẹ́)
2: Nigeria vs Cameroon (Felix Houphouet-Boigny Stadium, Aago mẹ́jọ àsálẹ́)
Ọjọ́ Àìkú, ọjọ kejìdínlọ́gbọ̀n, oṣù kínní :
3:…
Tanzania ṣetán fún ìfẹ̀hónúhàn alátakò, pè fún àtúnṣe ètò ìdìbò
Ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò pàtàkì ní Tanzania, Chadema, ti múra fún ìfèhónúhàn lórílẹ̀-èdè lórí òfin ètò ìdìbò tí wọ́n ń gbèrò, bí ìgbé ayé ṣe le, àti fífi àtúnṣe òfin orílẹ̀-èdè falẹ̀.
Niwọn igba ti…